Jump to content

Alekos Alekou

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Alekos Alekou(tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù Kejìlá ọdún 1983 ní Limassol, Cyprus) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ará Cyprus tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí olùgbá bọ́ọ̀lù fún Agiou Tychona.

Alekou ti gbá bọ́ọ̀lù fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹgbẹ́ ní Ẹ̀ka Àkọ́kọ́ Kípírọ́sìàti fún Iraklis ní Super League Greece. Alekou kọ́kọ́ gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ orílẹ̀-èdè Cyprus ní ọdún 2005 nígbà tí ó dojú kọ Wales.

Ní ọjọ́ kẹwàá oṣù karùn-ún ọdún 2016, ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ KTP ti Finland. Lẹ́yìn tí Alekou ti gbá bọ́ọ̀lù márùn-ún péré fún KTP nítorí àwọn ìpalára, ó gbà pẹ̀lú ẹgbẹ́ rẹ̀ ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 2016 láti fòpin sí àdéhùn rẹ̀. [1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Page Àdàkọ:Reflist/styles.css has no content.

  1. ↑ Empty citation (help)