Alexendra johnes
| Alexandra Johnes | |
|---|---|
Alexandra Johnes at the 73rd Annual Peabody Awards in 2014 | |
| Iṣẹ́ | Producer (film), actor |
| Ìgbà iṣẹ́ | 1987–present |
Alexandra Johnes (tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù Kejìlá, ọdún 1976) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tí ó máa ń ṣe àgbékalẹ̀ àwọn fíìmù ìwé-ẹ̀rí (documentary films) àti ẹni tí ó ti fìgbà kan jẹ́ òṣèrébìnrin. Gẹ́gẹ́ bí olùgbékalẹ̀ fíìmù, a mọ Johnes fún àwọn iṣẹ́ bíi *The Square*, *Gonzo: The Life and Work of Dr. Hunter S. Thompson*, àti *Doubletime*. Ó ti ṣiṣẹ́ pọ̀ gẹ́gẹ́ bí olùgbékalẹ̀ fíìmù pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olùdarí fíìmù, títí kan Alex Gibney, Eugene Jarecki, àti Jehane Noujaim. Ní ọdún 2013, Johnes gba àmì-ẹ̀yẹ Primetime Emmy fún ṣíṣe àgbékalẹ̀ fíìmù *Mea Maxima Culpa: Silence in the House of God*. Nígbà tí ó wà ní iṣẹ́ òṣèré, àwọn ipa pàtàkì tí ó kó nínú fíìmù pẹ̀lú ipa "Childlike Empress" nínú *The NeverEnding Story II: The Next Chapter* àti ipa "Phoebe" nínú *Zelly and Me* (níbi tí ó ti kópa pẹ̀lú Isabella Rossellini àti David Lynch), àti àwọn ipa kékeré nínú àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù bíi *Buffy the Vampire Slayer* àti *Sabrina, the Teenage Witch*[1]..
Ìtàn ìgbésí ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Johnes gba ìwé-ẹ̀rí BFA láti Tisch School of the Arts ní New York University (NYU). Láàárín ọdún 2007 sí 2012, Johnes ṣiṣẹ́ ní Jigsaw Productions fún olùdarí fíìmù Alex Gibney, ẹni tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Award; ó sì ń bójútó àwọn apá pàtàkì nínú ìgbékalẹ̀ àti ṣíṣe àwọn fíìmù náà. Ní ọdún 2012, Johnes gba àǹfààní ìdánilẹ́kọ̀ọ́ "Transatlantic Partnership (TAP) Producing Fellowship" láti ọ̀dọ̀ àjọ Independent Filmmaker Project..[2]
Johnes ni o n dari ile-iṣẹ iṣelọpọ Special Projects[1]..
Stephanie Johnes, tí í ṣe arábìnrin Johnes, náà tún máa ń ṣiṣẹ́ nínú iṣẹ́ fíìmù. Stephanie ló darí tí ó sì ya àwòrán fíìmù ìwé-àkọsílẹ̀ ọdún 2007 tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ *Doubletime*, èyí tí Alexandra sì ṣiṣẹ́ lórí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùgbéjáde.[1].
Àkójọ àwọn fíìmù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Producer
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]| Year | Title | Role | Notes |
|---|---|---|---|
| 2017 | The Mars Generation | Executive producer | |
| 2016 | Holy Hell | Producer | |
| 2015 | Frame by Frame | Executive producer | |
| 2015 | The Witch | Executive producer | |
| 2013 | The Square | Co-producer/Executive producer | |
| 2012 | The House I Live In | Consulting producer | |
| 2012 | Mea Maxima Culpa: Silence in the House of God | Producer | |
| 2012 | Rafea: Solar Mama | Supervising producer | |
| 2011 | Magic Trip: Ken Kesey's Search for a Kool Place | Producer | |
| 2011 | The Last Gladiators | Co-producer | |
| 2011 | Reagan | Consulting producer | |
| 2010 | Casino Jack and the United States of Money | Co-producer | |
| 2010 | Client 9: The Rise and Fall of Eliot Spitzer | Production executive | |
| 2010 | Freakonomics: The Movie | Segment producer | |
| 2010 | My Trip to Al-Qaeda | Producer | |
| 2009 | Money-Driven Medicine | Production executive | |
| 2008 | Gonzo: The Life and Work of Dr. Hunter S. Thompson | Production executive | |
| 2007 | Doubletime | Producer, Sound recordist |
Actor
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]| Year | Title | Role | Notes |
|---|---|---|---|
| 1988 | Zelly and Me | Phoebe | |
| 1990 | The NeverEnding Story II: The Next Chapter | Childlike Empress | |
| 1997 | Sabrina, the Teenage Witch | Hillary | episode: Hilda and Zelda: the Teenage Years (S1E15) |
| 1997 | Buffy the Vampire Slayer | Sheila Martini | episode: School Hard (S2E3) |
Awards ati yiyan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]| Year | Award | Category | Title of work | Result |
|---|---|---|---|---|
| 2013 | Primetime Emmy Award | Exceptional Merit in Documentary Filmmaking | Mea Maxima Culpa: Silence in the House of God | Won |
| 2017 | Gerald Loeb Award | Audio | "Dov Charney’s American Dream"[1] | Won |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 1 2 3 4 "UCLA Anderson School of Management Announces 2017 Gerald Loeb Award Winners". UCLA Anderson School of Management. June 27, 2017. Retrieved January 31, 2019.
- ↑
"2012 Project Forum Slate". Independent Filmmaker Project. August 10, 2012. Archived from the original on November 4, 2013. Retrieved March 9, 2014. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - "New York Film Academy: Faculty, Documentary Department". Archived from the original on August 29, 2013. Retrieved March 9, 2014 – via Internet Archive.
- "Jigsaw Productions: Staff and Collaborators". Archived from the original on October 17, 2013. Retrieved March 9, 2014 – via Internet Archive.
- "Noujaim Films Presents:Rafea: Solar Mama" (PDF) (Press release). Noujaim Films. January 29, 2014. Archived from the original (PDF) on March 9, 2014. Retrieved March 9, 2014 – via Internet Archive.
-
"Alexandra Johnes". veryspecialprojects.com. Archived from the original on March 9, 2014. Retrieved March 9, 2014. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) -
"IFP International Fellowships". Independent Filmmaker Project. March 3, 2013. Archived from the original on October 1, 2013. Retrieved March 9, 2014. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - Obenson, Tambay A. (August 29, 2012). "Indiewire: Award-Winning Doc 'Doubletime' Coming To DVD, VOD, Digital Download On September 25". IndieWire. Archived from the original on March 4, 2016. Retrieved March 9, 2014 – via Internet Archive.
- "Emmys - Mea Maxima Culpa: Silence in the House of God". Retrieved February 25, 2014.
<ref> tag with name "NYFAbio" defined in <references> is not used in prior text.Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tag with name "jigsawbio" defined in <references> is not used in prior text.Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tag with name "rafeabio" defined in <references> is not used in prior text.Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tag with name "specialprojectsbio" defined in <references> is not used in prior text.Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tag with name "ifpTAP" defined in <references> is not used in prior text.Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tag with name "indiewireDoubletime" defined in <references> is not used in prior text.Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tag with name "emmys" defined in <references> is not used in prior text.External links
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Àdàkọ:IMDb name
- "Dov Charney’s American Dream", 2017 Gerald Loeb Award winner for Audio