Jump to content

Aliassou Sanou

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Aliassou Sanou
Personal information
Ọjọ́ ìbí24 Oṣù Kàrún 1988 (1988-05-24) (ọmọ ọdún 38)
Ibi ọjọ́ibíOuagadougou, Burkina Faso
Ìga1.90 m[1]
Playing positionMidfielder[2]
Senior career*
YearsTeamApps†(Gls)†
2013–2016AS SONABEL
2016Sunshine Stars
2017Rivers United19(0)
2018Lobi Stars5(0)
2018–2020Salitas FC13(0)
2020–2021USFA2(0)
National team
2014–2015Burkina Faso3(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Aliassou Sanou (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1988) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Burkinabe tẹ́lẹ̀ tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù àárín gbùngbùn.

Iṣẹ́ Ìṣe Gégébí Agbábóólù kárí ayé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní oṣù kìíní ọdún 2014, Brama Traore, ẹni tí ńṣe olùkọ́ni fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Burkina Faso pè é láti darapọ̀ mọ́ ẹgbé agbábóòlù Burkina Faso fún ìdíje African Nations Championship ti ọdún 2014.[3][4] Nínú idije òun, egbẹ́ agbábóòlù Burkina Faso ja ní ìpele ìkínni lẹ́yìn tí egbe agbábóòlù Uganda àti Zimbabwe lù wọ́n, tí wọ́n sì jó gbá dọ́gba-dọ́gba pelu ikò agbábóòlù Morocco.[5][6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ Àdàkọ:NFT
  2. ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named "gsddf".
  3. ↑ "CHAN 2014: the 23-man squad of Burkina Faso". modernghana.com. Retrieved 13 March 2014.
  4. ↑ "CHAN 2014 Preview: GROUP B". allsports.com.gh. Archived from the original on 13 March 2014. Retrieved 13 March 2014. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. ↑ "CHAN 2014 Preview: GROUP B". allsports.com.gh. Archived from the original on 13 March 2014. Retrieved 13 March 2014. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. ↑ "CHAN 2014 Preview: GROUP B". allsports.com.gh. Archived from the original on 13 March 2014. Retrieved 13 March 2014. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  • Aliassou Sanou at National-Football-Teams.com
  • Aliassou Sanou at WorldFootball.net