Alpha Condé
Jump to navigation
Jump to search
Alpha Condé | |
---|---|
President-elect of Guinea | |
Taking office November 2010 | |
Alákóso Àgbà | Jean-Marie Doré |
Succeeding | Sékouba Konaté (Acting) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹta 1938 Boké, French Guinea (now Guinea) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Rally of the Guinean People |
Alpha Condé (ojoibi 4 March 1938) je oloselu ara Guinea ati olori egbe oloselu Rally of the Guinean People (RPG). O je ojogbon sayensi oloselu ni University of Paris, o si lo opo odun bi alatako si awon ijoba ni Guinea, o si kopa laiyori fun ipo aare lodi si Aare Lansana Conté ninu awon idiboyan aare 1993 ati 1998. Ninu idiboyan aare odun 2010 o je didiboyan wole gege bi Aare ile Guinea.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |