Jump to content

Amaechi Muonagor

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Amaechi Muonagor
Ọjọ́ìbí(1962-08-20)20 Oṣù Kẹjọ 1962
Obosi, Anambra State, Nigeria
Aláìsí24 March 2024(2024-03-24) (ọmọ ọdún 61)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Nigeria, Nsukka
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1989–2024
Àwọn ọmọ4

Amaechi Muonagor (20 August 1962 – 24 March 2024) fìgbà kan jẹ́ àgbà òṣèrẹ́kùnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, adẹ́rìn-ín pòṣónú, àti olùgbé fíìmù àgbéléwò jáde. Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ ti Africa Magic Viewers Choice ní ọdún 2017, gẹ́gẹ́ bí òṣèrẹ́kùnrin tó dára jù lọ. Ó darapọ̀ mọ̀ isẹ́ tíátà ní ọdún 1998, ó sì ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọl fíìmù bí i Taboo 1 (1989), Aki and Pawpaw, Karishika (1998), àti Aki na Ukwa (2002), Igodo (1999).[1]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Amaechi Muonagor sí ìlú Obosi, tó wà ní apa Àríwá ti agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ti Idemili, ní ìpínlè Anambra. Ó lọ sí St. Mary's Primary School, ní Obosi, àti Oraifite Grammar School kí ó ṣẹ̀ tó lọ sí University of Nigeria, Nsukka (UNN) ní ìpínlẹ̀ Enugu láti lọ kẹ́kọ̀ọ́ níoa Ètò ọrọ̀-ajé, tí ó sì kékọ̀ọ́ jáde ní ọdún 1987.[2]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Taboo 1 (1989)
  • Blood Money (1997)
  • Oracle (1998) bíi Igwe
  • Karishika (1998) bíi Minister Jonathan
  • Igodo (1999)[3]
  • The Last Burial (2000)
  • Issakaba (2000) bíi Igwe
  • Vanity Upon Vanity (2000) bíi Egwu
  • Executive Crime (2000) bíi Chief Inspector
  • Married to a Witch (2001) bíi Papa
  • Aki na Ukwa (2002) bíi Mbakwe
  • Charge & Bail (2003) bíi Jephtah
  • Cold War (2005) bíi Odimba
  • Desperate Women (2006) bíi Jude
  • End of Evil Doers (2007) bíi Igwe Onyima
  • His Last Action (2008) bíi David
  • Sincerity (2009) bíi Chief Ezekwe
  • Without Goodbye (2009) bíi Chief Rufus
  • Most Wanted Kidnappers (2010) bíi Utu
  • Jack and Jill (2011) bíi Amadi
  • Village Rascal (2012)
  • August Meeting (2012) bíi Mazi Igwemba
  • Ihite Kingdom (2014) bíi Alfred
  • Evil World (2015)[4]
  • Ugonma (2015)[5]
  • Code of Silence (2015)[6]
  • Spirits (2016)
  • Rosemary (2016)
  • The Bushman I Love (2017) bíi Chief Mmili
  • High Stakes (2019) bíi Pius
  • My Village People (2021)[7] as Ndio
  • Aki and Pawpaw (2021) bíi Mazi Mbakwe
  • Fishers of Wealth (2023) bíi Obiakor

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Mirilla, Dennis Da-ala (2024-03-24). "Remembering Amaechi Muonagor – 10 movies that defined a Nollywood legend". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-03-24. 
  2. Onoja, Simeon (2024-03-19). "A Spotlight on Veteran Actor Amaechi Muonagor As He Battles Kidney Disease". Business Elites Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-03-25. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. Izuzu, Chidumga. "#ThrowbackThursday: 17 years after, "Igodo" deserves a remake - Movies - Pulse" (in en-US). http://pulse.ng/movies/throwbackthursday-17-years-after-igodo-deserves-a-remake-id5703484.html. 
  4. Amodeni, Adunni. "Married Nollywood Actor Impregnates Younger Lover In Evil World (VIDEO)" (in en-US). Naij.com - Nigeria news.. https://entertainment.naij.com/640253-married-nollywood-actor-impregnates-younger-lover-evil-world-video.html. 
  5. Bada, Gbenga. "Chioma Chukwuka Akpotha: Actress joins Francis Duru and Amaechi Muonagor on movie set - Movies - Pulse" (in en-US). http://pulse.ng/movies/chioma-chukwuka-akpotha-actress-joins-francis-duru-and-amaechi-muonagor-on-movie-set-id3613450.html. 
  6. "'Code of Silence' tackles rape...with doses of humour – By Toni Kan - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games" (in en-GB). Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games. 17 August 2015. https://thenet.ng/opinion-emem-isongs-code-of-silence-tackles-rapewith-doses-of-humour/. 
  7. Nwogu, Precious (31 May 2021). "Watch the official trailer for 'My Village People'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 8 June 2021.