Amina (fiimu 2012)
Ìrísí
| Amina | |
|---|---|
| Fáìlì:Amina 2012 film.jpg Theatrical poster | |
| Adarí | Christian Ashaiku |
| Olùgbékalẹ̀ | Christian Ashaiku Wil Johnson |
| Òǹkọ̀wé | Christian Ashaiku |
| Àwọn òṣèré | |
| Orin | Warren Bennett Sam Bergliter |
| Ìyàwòrán sinimá | Andrei Austin Neil Johnson |
| Olóòtú | Liz Webber |
| Ilé-iṣẹ́ fíìmù | AOC Communication |
| Olùpín | Talking Drum Entertainment |
| Déètì àgbéjáde |
|
| Àkókò | 93 minutes |
| Orílẹ̀-èdè | Nigeria United Kingdom |
| Èdè | English |
Amina jẹ́ eré tí wọ́n ṣe àgbéjáde ní ọdún un 2012 ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà Eré Ọpọlọ ní eré yìí ni written, produced, and directed by Christian Ashaiku ló kọ ó, lo darí ẹ̀, ló sì tún àgbéjáde rẹ̀, àwọn òṣèré tó kópa nínú eré yìí ni Omotola Jalade Ekeinde, Van Vicker, and Alison Carroll. Amina was shot on location in London.[1][2]
Àwọn Òṣèré Akópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Omotola Jalade Ekeinde kópa gẹ́gẹ́ bíi Amina
- Wil Johnson kópa gẹ́gẹ́ bíi Dr Johnson
- Van Vicker kópa gẹ́gẹ́ bíi Michael
- Vincent Regan
- Alison Carroll kópa gẹ́gẹ́ bíi Lucy
- Susan Mclean kópa gẹ́gẹ́ bíi Nọ́ọ̀sì
- Charlie Buck kópa gẹ́gẹ́ bíi Shakespeare Lady
- Jonathan Cohen kópa gẹ́gẹ́ bíi Stunt Performer
- Sophia Leonie kópa gẹ́gẹ́ bíi Kate
- Suzann McLean kópa gẹ́gẹ́ bíi Gina Johnson
- Aatif Nawaz kópa gẹ́gẹ́ bíi Òṣìṣẹ́
- Jenny Walters kópa gẹ́gẹ́ bíi Queenie
Ìgbàwọlé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eré yìí Amina gba àyẹ̀wò lóríṣiríṣi, Ó sì tún gba ìbẹnu-àtẹ́-lù, púpọ̀ nínú àwọn tí wọ́n ṣe lámèyítọ́ lórí eré náà ni wọ́n fi ẹ̀sùn kàn ìyàn àwọn oṣèré nínú fíìmù náà. NollywoodForever fún un ní ìdíje 45%, wọ́n tún bu ẹnu àtẹ́ lu àwọn òṣèré tí wọ́n yàn fún eré náà.[3]
Ẹ tún lè wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Akojọ awọn fiimu Naijiria ti ọdun 2012
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "UK Premiere of Amina movie". 360nobs. October 18, 2012. Archived from the original on 8 August 2020. Retrieved 9 February 2014. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - ↑ "Amina film". Gistus. 13 April 2012. Retrieved 9 February 2014.
- ↑ "Nollywood Forever reviews Amina Movie". Nollywood Forever. February 13, 2013. Archived from the original on 23 October 2020. Retrieved 9 February 2014. Unknown parameter
|url-status=ignored (help)
Ita ìjápọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ẹ̀ka:
- Template film date with 1 release date
- Pages with citations using unsupported parameters
- 2012 films
- English-language Nigerian films
- 2012 Nigerian films
- 2010s psychological drama films
- Films about psychiatry
- Films set in England
- Films shot in England
- Nigerian drama films
- 2012 drama films
- 2012 English-language films
- English-language drama films