Jump to content

Aminu Ibrahim Daurawa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Aminu Ibrahim Daurawa (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kìíní oṣụ̀ kìíní ọdún 1969) tí àwọn ènìyàn tún máa ń pè ní Sheikh Daurawa, jẹ́ onímọ̀ Islam àti ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ìpínlè Kano.[1] Bàbá rẹ̀ ni gbagbúgbajà oníṣẹ́-ìwádìí, ìyẹn Sheikh Ibrahim Muhammad Mai Tafsiri, Sheikh Daurawa èyí ti gómìnà ìpínlè Kano tí í ṣe Abba Kabir Yusuf yàn gẹ́gẹ́ bí commander Hisbah Kano, ní ọdún 2023.[2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí i ní ọjọ́ kìíní oṣụ̀ kìíní ọdún 1969, sí agbègbè ìjọba ìbílè Mazugal Dala, ní Ipinle Kano, ní orílè-èdè Nàìjíríà.[4][5]

Ní ọdún 2004, ó lọ sí Bayero University, Kano níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa Mass Communication, bí ó ti ẹ̀ jẹ́ pẹ́ kò kẹ́kọ̀ọ́ náà jáde. Lẹ́yìn náà ni ó lọ sí Benin private university, èyí tí ó ní ẹ̀ka ní Kano, àmọ́ kò parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ níbẹ̀ bákan náà.[6][7][8]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Musa, Aisha (2022-12-28). "Daurawa ya shawarci maza masu son kara aure da kada su shekara 10 da mace 1". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Hausa). Retrieved 2023-05-11. 
  2. Sadiq (10 July 2023). "Abba Ya Sake Nada Sheikh Daurawa Shugaban Hisbah Ta Kano" (in ha). Leadership Hausa. https://hausa.leadership.ng/abba-ya-sake-nada-sheikh-daurawa-shugaban-hisbah-ta-kano/. Retrieved 10 July 2023. 
  3. "Abba ya mayar da Sheikh Daurawa kan shugabancin Hisba ta Kano" (in ha). BBC Hausa. 10 July 2023. https://www.bbc.com/hausa/live/labarai-66152493?. Retrieved 10 July 2023. 
  4. Shibayan, Dyepkazah (24 February 2017). "Cleric to Sanusi: Your proposal on polygamy will violate the Quran". The cable.ng. https://www.thecable.ng/cleric-sanusi-proposal-polygamy-will-violate-quran/amp. Retrieved 25 February 2022. 
  5. "We never Married Ese To Yunusa"- Sheik Aminu Daurawa, Hisbah Boss" (in English). icirnigeria.org. 11 March 2016. https://www.icirnigeria.org/we-never-married-ese-to-yunusa-sheik-aminu-daurawa-hisbah-boss/www.icirnigeria.org/we-never-married-ese-to-yunusa-sheik-aminu. Retrieved 17 February 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  6. "Ku san Malamanku: Tare da Sheikh Aminu Ibrahim Daurawa". BBC Hausa. 30 October 2020. https://www.bbc.com/hausa/rahotanni-54560258. Retrieved 17 February 2022. 
  7. Rasheed, Abdul Rahman (7 October 2021). "Yin lalata kafin aure da kuma aure bayan lalata, Sheikh Aminu Daurawa". legit.hausa.ng. https://hausa.legit.ng/1437761-yin-lalata-kafin-aure-da-kuma-aure-bayan-lalata-sheikh-aminu-daurawa.html. Retrieved 17 February 2022. 
  8. "Eight Categories Of Unmarried Women In Kano – Sheikh Daurawa" (in English). daily trust.com. 11 March 2017. https://dailytrust.com/eight-categories-of-unmarried-women-in-kano-sheikh-daurawa. Retrieved 17 February 2022.