Ango Abdullahi
Ìrísí
Ango Abdullahi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 13 December 1938 Old Giwa Village, Kaduna |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ibadan, Ahmadu Bello University |
Olólùfẹ́ | Senator Aisha Alhassan |
Àwọn ọmọ | Ango Sadiq Abdullahi |
Awards | Commander of the Order of the Niger (CON), Magajin Rafin Zazzau |
Ango Abdullahi je ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà omowe ati oloselu. O jẹ Igbakeji Yunifasiti ti Ahmadu Bello nígbà kàn ri ati pè o ti jẹ aṣoju ẹkun ìdìbò Iwọ-oorun Zaria tẹlẹ ni ipinlẹ Kaduna. [1] [2]
Igbesi aye ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ango Abdullahi je Musulumi o si je bàbá Ango Sadiq Abdullahi omo ile aṣojú.[2]
Eto ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O bẹrẹ eko alakọbẹrẹ ni Kali Elementary School ni ọdun 1944 kí ó tó dadasi ilé-ìwé Giwa Elementary School ni ọdun kan na. O lọ si ile-ẹkọ Barewa college laarin ọdun 1953 sì ọdun 1958, ó kàwé gboyè ni unifasiti Ibadan àti Ahmadu Bello University Zaria kí ó tó di adarí àgbá ni ile eko Ahmadu Bello Zaria.[3]