Annabella Zwyndila
Ìrísí
Annabella Zwyndila | |
---|---|
Annabella Zwyndila photo shoot | |
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kọkànlá 1992 Ibadan, Oyo, Nigeria |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Jos |
Iṣẹ́ | Actress, model, singer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2012—present |
Awards | ZAFAA Awards as Best Upcoming Actress |
Annabella Zwyndila jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó gbajúmọ̀ káàkiri gẹ́gẹ́ bi Ms Green.
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Annabella Zwyndila ní ̀ilú Ìbàdàn, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ ẹgbẹ́ ọmọ ogun ti Nàìjíríà, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ òṣíṣẹ́ àgbà nídi ṣíṣe ètò ẹ̀kọ́ àwọn ará ìlú. Ó lọ sí ilé-ìwé Command Secondary School ní ìlú Jos, Ìpínlẹ̀ Plateau ṣááju kí ó tó lọ sí Yunifásitì ìlú Jos níbití ó ti gba oyè ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ eré ìtàgé ṣíṣe.
Àkójọ àwọn eré tí ó ti kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọ́lé | Ipa | Ọdún |
---|---|---|
Samantha | Samantha | 2012 |
Twisted Union | Chantel | 2013 |
Free to Live (Super Story) | Turai | 2017 |
RedBox | Queen Shagbo | 2017 |
New Jerusalem | Charity | |
Last Men Of New Jerusalem | Charity | |
Painful Sin | 2010 | |
Common Grounds | Ann | 2012 |
Mario Mario | 2014 | |
Amstel Malta Box Office (AMBO 3) | Reality Show | 2007 |
Àwọn ìyẹ́sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ZAFAA Awards as Best Upcoming Actress[1]