Jump to content

Anno Domini

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

AD tumo si «Anno Domini» o je Latina, itumo ni èdè Yoruba wa «Ni odun ti Olugbala ti dé» Awa n lo AD lati mo awon ohun ti wa sele lehin Olugbala tabi Jesu Kristi ti dé tabi ti bi.