Jump to content

Arthémon Hatungimana

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Arthémon Hatungimana
Burundian Athlete, Arthémon Hatungimana
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbíOṣù Ṣẹ̀rẹ́ 21, 1974 (1974-01-21) (ọmọ ọdún 52)
Muhweza, Karuzi, Burundi
Height1.80 m (5 ft 11 in)
Weight65 kg (143 lb)
Sport
Erẹ́ìdárayáRunning
Event(s)800 metres

Àdàkọ:Citations needed

Artémon Hatungimana (ti wón bi ni ọjọ kọkànlélógún oṣù kìíní ọdún 1974) [1] jẹ ọmọ orílẹ̀ èdè Burundi tí ó jẹ́ olusare aarin-jinna tẹlẹ. Ní ọdún 1995, ó gba Àmì ẹ̀yẹ fàdákà níbi ìdíje ti 800 mítà ní ìdíje àgbáyé ní eré ìdárayá .[2]

Àwọn Akọsílẹ̀ Eré ìje re

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Unreferencedsect

Gégébí Aṣojú fún  Burundi
1992 World Junior Championships Seoul, South Korea 9th (sf) 400 m 46.78
1993 African Championships Durban, South Africa 3rd 800 m 1:46.42
1994 Jeux de la Francophonie Bondoufle, France 4th (h) 800 m 1:50.561
1995 World Indoor Championships Barcelona, Spain 10th (h) 800 m 1:50.17
World Championships Gothenburg, Sweden 2nd 800 m 1:45.64
All-Africa Games Harare, Zimbabwe 1st 800 m 1:47.42
1996 Olympic Games Atlanta, United States 7th (sf) 800 m 1:44.92
1997 World Championships Athens, Greece 19th (qf) 800 m 1:46.64
Jeux de la Francophonie Antananarivo, Madagascar 1st 800 m 1:46.83
1998 African Championships Dakar, Senegal 6th 800 m 1:47.63
1999 World Indoor Championships Maebashi, Japan 8th (sf) 800 m 1:48.17
World Championships Seville, Spain 25th (h) 800 m 1:47.08
2000 Olympic Games Sydney, Australia 36th (h) 800 m 1:48.14
2001 World Championships Edmonton, Canada 5th (sf) 800 m 1:45.21
2002 African Championships Radès, Tunisia 7th 800 m 1:51.27
2003 World Championships Paris, France 26th (h) 800 m 1:46.35
All-Africa Games Abuja, Nigeria 18th (h) 800 m 1:53.16
2004 Olympic Games Athens, Greece 23rd (h) 800 m 1:46.35

1Did not start in the final

Àkọsílẹ̀ àwọn àkókò eré ìje rẹ tó dára jùlọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ Sports-Reference profile
  2. ↑ "Arthémon HATUNGIMANA | Profile | World Athletics". worldathletics.org. Retrieved 2025-12-14.