Arugbá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Arugba
Fáìlì:Arugba Movie Poster.jpg
arugba movie poster se
AdaríTunde Kelani
Olùgbékalẹ̀Mainframe Productions
Òǹkọ̀wéyemi Peter Badejo Segun Adefila Kareem Adepoju Lere Paimo
OrinWole Oni Adunni & Nefretiti Segun Adefila
Ìyàwòrán sinimáLukman AbdulRahman
OlóòtúFrank Anore Hakeem Olowookere
Déètì àgbéjáde
  • 2008 (2008)
Àkókò95 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèYoruba
Ìnáwó₦22 million[1]

Arugbá jẹ́ gbankọgbì sinimá àgbéléwò kan tí gbajúmọ̀ olóòtú àti olùdarí, Túndé Kèlání gbé jáde lọ́dún 2008. Sinimá yìí dá lórí àṣà Arugbá tí ó máa ń wáyé nínú ọdún ìbílẹ̀ kan tí wọ́n máa ń ṣe ní ìlú Òṣogbo, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Ọ̀ṣun Òṣogbo. Gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, Bùkọ́lá Awóyẹmí tí ó fẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré Dàmọ́lá Ọlátúnji ni ó kópa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn Arugbá nínú sinimá náà.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Abulude, Samuel (31 May 2014). "Pirates Have Made Movie Makers Paupers– Tunde Kelani". Leadership. Leadership Newspapers. Archived from the original on 22 April 2016. Retrieved 29 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)