Asele Woy
Ìrísí
| Òrọ̀ ẹni | |
|---|---|
| Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
| Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Kínní 1959 Emoh Abua, Nigeria |
| Sport | |
| Erẹ́ìdárayá | Sprinting |
| Event(s) | 4 × 400 metres relay |
Asele Disep Woy (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kìíní ọdún 1959) jẹ́ Asáré orí páápá eléré ìje ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó kópa nínú dije ere ije mita 4 × 400 ti awọn obinrin ni Olimpiiki Igba Ooru ti ọdun 1980.[1]