Asha-Rose Migiro
Ìrísí
Asha-Rose Mtengeti Migiro | |
---|---|
3rd Deputy Secretary-General of the United Nations | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga February 5, 2007 | |
Asíwájú | Mark Malloch Brown |
Foreign Minister of Tanzania | |
In office January 4, 2006 – January 11, 2007 | |
Asíwájú | Jakaya Kikwete |
Arọ́pò | Bernard Membe |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 9 Oṣù Keje 1956 Songea, Ruvuma Region, Tanzania |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Tanzanian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Chama Cha Mapinduzi |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Cleophas Migiro |
Profession | Lawyer and politician |
Asha-Rose Mtengeti Migiro (ojoibi July 9, 1956 ni Songea, Ruvuma Region, Tanzania) je agbejoro ati oloselu ara Tanzanian. Ni January 5, 2007, o je sisodi Igbakeji Akowe Agba Aparapo awon Orile-ede.[1] O bere ise ni February 1.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Associated Press authors (2007-01-05). "Tanzania's Migiro is U.N. deputy". www.cnn.com (CNN). Archived from the original on 2007-01-07. http://www.cnn.com/2007/WORLD/africa/01/05/un.deputy.ap/index.html. Retrieved 2007-01-06.
- ↑ "New UN Deputy Secretary-General takes oath of office", Xinhua (People's Daily Online), February 6, 2007.