Jump to content

Atilio Aguirre

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Atilio Antonio Aguirre
Personal information
Playing positionForward
Senior career*
YearsTeamApps†(Gls)†
1959–1962The Strongest
1962–1964Deportivo Municipal
1965The Strongest4(0)
1966Deportivo Municipal10(3)
National team
1959–1965Bolivia12(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

 

Antonio Atilio Aguirre (kú kí ó tó di oṣù kẹta ọdún 2003) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ará Bolivia. Ó jẹ́ ara ẹgbẹ́ ọmọ ogun Bolivia tí wọ́n gba ife-ẹ̀yẹ Àṣeyọrí Gúúsù Amẹ́ríkà ní ọdún 1963 ní ilẹ̀ wọn.

Iṣẹ́ kárí ayé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aguirre jẹ́ ara ẹgbẹ́ Bolivia fún ìdíje aṣeyọrí Gúúsù Amẹ́ríkà ní Argentina ní ọdún 1959.   Ó ṣe eré mẹ́rin nínú ìdíje náà,  lòdì sí Uruguay, Argentina, Chile àti Peru [1] bí Bolivia ṣe parí ìdíje ìkẹyìn.

Aguirre tún wà lára àwọn ẹgbẹ́ Bolivia fún ìdíje aṣeyọrí Gúúsù Amẹ́ríkà ti ọdún 1963 tí wọ́n ṣe ní ilẹ̀ wọn. Ó ṣe eré kan ṣoṣo nínú ìdíje náà, lòdì sí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Colombia, [2] bí Bolivia ṣe gba ìdíje náà, àmì-ẹ̀yẹ kan ṣoṣo tí ó ní títí di òní yìí.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Page Àdàkọ:Reflist/styles.css has no content.

  1. ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named "Southamerican".
  2. ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named "Southamerican Championship 1963".