Azubuike Okechukwu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Azubuike Godson Okechukwu (bí ní Ọjọ́ kọnkàndínlógún Oṣù kẹ́rin Ọdún 1997) jẹ́ alágbàṣe agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ Yeni Malatyaspor ti Turkey, gẹ́gẹ́ bí a gbá ipò àárín.

Ìrìnàjò iṣẹ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bíi ní ìlú Katsina, Okechukwu  gbá bọ́ọ̀lù fún Bayelsa United àti Yeni Malatyaspor.[1][2]

Ìrìnàjò iṣẹ́ rẹ̀ ní ilú òkèèrè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Okechukwu gbá bóòlù ní ìgbà àkọ́kọ́ fún Nigeria ní ọdún 2016,[1] a yàn fún ìpèsè eléni márùndínlógójì fún ọdún 2016 Summer Olympics.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Azubuike Okechukwu".
  2. Azubuike Okechukwu profile at Soccerway.
  3. Oluwashina Okeleji (24 June 2016).