Jump to content

Babatunde Elegbede

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Muftau Adegoke Babatunde Elegbede
Governor of Cross River State
In office
28 July 1978 – 30 September 1979
AsíwájúPaul Omu
Arọ́pòClement Isong
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíc. 1939
Aláìsí19 June 1994

Muftau Adégòkè Babátúndé Elégbèdé (c. 1939 - 19 June 1994) òun náà tún ni Túnde Elégbèdé. Ó jẹ́ ọ̀gá ológun ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River nígbà kan rí.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]