Badagri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Badagri
Ìlú
A chair market at Badagry in 1910.
A chair market at Badagry in 1910.
Orílẹ̀-èdè  Nàìjíríà
Website http://www.badagrygov.org/

Badagri tabi Agbada-rigi je olu-ilu nla kan ati ijoba ibile fun awon ilu agbegbe re pelu ti o wa ni erekusu ipinle Eko. Bakan naa ni o tun je ibode fun ile olominira Naijiria pelu ile olominira Benin ti Seme si je iloro fun awon ilu mejeeji. Iye awon eniyan ti o wa ni Badagiri gege bi ikaniyan odun 2006 ti so je 241,093. Gege bi ile Yoruba, oruko Oba Agbada-rigi ni Aholu Mahitonyi.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]