Basirat Nahibi
Ìrísí
Basirat Nahibi | |
---|---|
Orúkọ míràn | Basirat Nahibi-Niasse |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iṣẹ́ | Politician, entrepreneur |
Organization | Women Advancement for Economic and Leadership in Africa (WAELE) |
Political party | All Progressives Congress |
Basirat Nahibi tàbí Basirat Nahibi-Niasse jẹ́ òṣèlú, oníṣòwò àti òṣèlú-bìnrin àkọ́kọ́ to díje fún ipò gómìnà l'órílẹ́-èdè Nigeria. [1][2]
Òun olùdásílẹ̀ Women Advancement for Economic and Leadership in Africa (WAELE);[3][4] ẹgbẹ́ tí kò sì fún èrè jíjẹ tó ń ró àwọn obìnrin ilẹ̀ adúláwò lágbára nínú ọ̀rọ̀ ètò ajé àti ìṣèlú, tí ó sì máa ń jẹ́ kí wọ́n kópa nínú ìpẹ̀tùsáwọ̀ káàkiri orílẹ̀-èdè méjìlẹ̀láàádọ́ta (52) ní Africa. Bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress.[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "First Female – firstnigerian". Google. Retrieved 12 May 2019.
- ↑ Alqali, Adam (25 February 2019). "INTERVIEW: "WAELE AFRICA raising the voices of African women, through economic empowerment" – Basirat Nahibi-Niasse". African Newspage. Retrieved 12 May 2019.
- ↑ Newspapers, BluePrint (10 May 2019). "Ondo women group empowers widows with N2m". Blueprint. Retrieved 12 May 2019.
- ↑ "High turnout at Aso Rock polling units, Kyari hails INEC". The Sun Nigeria. 23 February 2019. Retrieved 12 May 2019.
- ↑ "Leadership Newspaper – Nigerian News, Nigeria Newspapers". Leadership Newspaper. Retrieved 12 May 2019.