Basorun Gaa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Baṣọ̀run Gáà ni eré oriì ìtàgé tí Alàgbà Adébáyọ̀ Fàlétí kọ.

Ìwé eré oníṣe orì ìtàgé ni ìwé yìí. Ódá lórí Baṣọ̀run Gáà tìlú Ìbàdàn, ẹni tí ó jẹ́ afọbajẹ àti ayọba lóyè. Kókó inú ìwé ìtàn eré oníṣe yìí ni wípé kí a má ṣe ìkà. Ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá ni ònkọ̀wé náà fi kọ ìwé náà, tí ó sì gbé ìtàn rẹ̀ lé orí ìtàn gidi tí ó sì jẹ́ ojúlówó ìtàn ilé Yorùbá.

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Adebayo Faleti (1972), Basorun Gaa. Ibadan, Nigeria: Onibon-oje Press and Book Industries (Nig) Ltd. Oju-iwe = 149.