Benito Juárez

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Benito Jose Pablo Juárez García
Benito Juarez Presidente.jpg
Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò
Lórí àga
January 15, 1858 – April 10, 1864
Asíwájú Ignacio Comonfort
Arọ́pò Maximilian I of Mexico
Lórí àga
May 15, 1867 – July 18, 1872
Asíwájú Maximilian I of Mexico
Arọ́pò Sebastián Lerdo de Tejada
Alákóso Àgbà ilẹ̀ Mẹ́ksíkò
Lórí àga
April 10, 1864 – May 15, 1867
Monarch Maximilian I
Asíwájú Ararẹ̀
bíi Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò
Arọ́pò Ararẹ̀
bíi Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 21 Oṣù Kẹta, 1806(1806-03-21)
San Pablo Guelatao, Oaxaca
Aláìsí 18 Oṣù Keje, 1872 (ọmọ ọdún 66)
Mexico City, Federal District
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Liberal
Tọkọtaya pẹ̀lú Margarita Maza

Benito Juárez (Pípè: [beˈnito ˈxwaɾes]; (March 21, 1806 - July 18, 1872)[1][2] abiso si Benito Pablo Juárez García, je agbejoro ati oloselu omo Meksiko ti awon eniyan Zapotec lati Oaxaca to di Aare ile Meksiko ni emarun: 1858–1861 fun igba die, 1861–1865, 1865–1867, 1867–1871 ati 1871–1872.[3]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]