Blessing Uzzi
Ìrísí
Blessing Uzzi jẹ́ olùdarí fíìmù ọmọ orílè-èdè Naijiria, olóòtú ati olupilẹṣẹ fíìmù[1] ti o kàwé gba òye nípa ètò ẹ̀kọ́ Ìbátan Àgbáyé.[2] O gba ami eye fíìmù ati kikọ ti o dara julọ ni AMVCA 2025 Awards.[3][4][5] O da BluHouse Studios silẹ o si ṣe fiimu Freedom Way, fiimu kan ti o gba ami eye fiimu ti o dara julọ ni 2025 AMVCA Awards.[6][7] Iṣẹ rẹ lori Freedom Way ṣe afihan àwọn ìjàmbá tí ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ṣe fún àwọn ará ìlú.[8][9]
Àwọn iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Blessing Uzzi: Everything Around Me Inspires Me, Everything I Hear is Film – THISDAYLIVE" (in en-US). This Day. https://www.thisdaylive.com/2019/04/06/blessing-uzzi-everything-around-me-inspires-me-everything-i-hear-is-film/.
- ↑ Afolabi, Tobi (2025-07-14). "Blessing Uzzi is charting a course for authentic filmmaking in Nigeria". Marie Claire Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2025-10-09.
- ↑ Adebiyi, Oyindamola (2025-05-10). "All the 2025 AMVCA winners — here's who took home the awards!". Marie Claire Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2025-10-09.
- ↑ Medeme, Ovwe (2025-07-05). "Blessing Uzzi Leads New Zikoko Film Series, Life" (in en-GB). Independent (Lagos, Nigeria). https://independent.ng/blessing-uzzi-leads-new-zikoko-film-series-life/.
- ↑ Abioye, Damilare (2025-09-08). "Behind the Magic with Blessing Uzzi: The Creative Visionary Behind the Multi-Award-Winning 'Freedom Way'" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2025-10-09.
- ↑ ilesanmi, Tunrayo (2025-07-11). "Blessing Uzzi leads new film series, Life". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2025-10-09.
- ↑ Nwafor (2025-07-04). "Blessing Uzzi leads New Zikoko Film Series, 'Life'". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2025-10-09.
- ↑ Kwong, Wilson (2024-09-20). "Toronto International Film Festival 2024: Writer Blessing Uzzi And Director Afolabi Olalekan Of FREEDOM WAY". Film Inquiry (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2025-10-09.
- ↑ Adewoyin, Adeniyi (2025-08-01). "Blessing Uzzi: Freedom Way is inspired by personal encounter with police". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2025-10-09.
- ↑ "Blessing Uzzi Archives". The Lagos Review (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2025-08-10. Retrieved 2025-10-09.
- ↑ Agwaetiti Obiuto, Blues and Hills Pictures, 2018-05-05, retrieved 2025-10-09
- ↑ No Mans Land, Bluhouse Studios, retrieved 2025-10-09
- ↑ "Seun Kuti makes acting debut in Blessing Uzzi's forthcoming film | Pulse Nigeria". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2025-10-09.
- ↑ "Blessing Uzzi - Nollywire" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2025-10-09.