Bolaji Dada
Bolaji Dada | |
|---|---|
| Lagos State Commissioner for Women Affairs and Poverty Alleviation | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
| Ó gun orí àga 2019 | |
| Asíwájú | Joke Orelope- Adefulire |
| Àwọn àlàyé onítòhún | |
| Ọjọ́ìbí | Cecelia Bolaji Dada 9 Oṣù Keje 1966 Apapa |
| Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
| Alma mater | Lagos State University (BSc) Leeds Metropolitan University, (MSc) |
Cecelia Bolaji Dada fetisi ⓘ (a bí ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1966) jẹ́ igbákejì alága ìdí ìbílẹ̀ Apapa àti kọmíṣọ́nà lọ́wọ́lọ́wọ́ fún ọ̀ràn àwọn obìnrin àti ìdènà òṣì ní ìpínlẹ̀ Èkó.
Ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ ní ìbẹ̀rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bi Dada ni ilu Eko, o si gba oye B.Sc (Hon.) ninu kemistri ile-ise lati Yunifasiti Ipinle Eko ni odun 1991, o si tun gba oye oga ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ninu isakoso ile-ise lati Ile-ẹkọ giga Ìlú Ńlá Leeds ni odun 2009. [1]
Iṣẹ́ òṣèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìgbésẹ̀ Dada sí iṣẹ́ ìṣàkóso bẹ̀rẹ̀ nígbà tí wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ Ìgbìmọ̀ Eré Ìdárayá ti Ìpínlẹ̀ Èkó, lẹ́yìn náà ó di Akọ̀wé Àgbà àti Igbákejì Ààrẹ ti Ìjọ́ba Àgbègbè Apapa nígbà méjì [2] níbi tí ó ti gba ẹ̀bùn gẹ́gẹ́ bí Igbákejì Ààrẹ tó dára jùlọ ní Èkó ní ọdún 2010.
Lẹ́yìn náà, Gómìnà Sanwaolu yan Dada gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún Àwọn Obìnrin àti Ìdínkù Ìṣẹ́ ní ọdún 2020. [3] [4] [5] [6] [7]
Ìgbésí ayé ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dada ti ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú àwọn ọmọ.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ . Lagos, Nigeria.
- ↑ "Full list of Commissioners, Special Advisers in Sanwo-Olu Lagos govt". Lagos, Nigeria. https://dailypost.ng/2019/08/20/full-list-commissioners-special-advisers-sanwo-olu-lagos-govt/.
- ↑ "Sanwo-Olu swears in commissioners, special advisers". The Guardian (Lagos, Nigeria). Archived on 2019-08-21. Error: If you specify
|archivedate=, you must also specify|archiveurl=. https://guardian.ng/news/sanwo-olu-swears-in-commissioners-special-advisers/. - ↑ "Ambode's SSG, The Nation's Editor, 23 others make Sanwo-Olu's list of Commissioners, Special Advisers". Daily Trust. 2019-07-14. https://www.dailytrust.com.ng/ambodes-ssg-the-nations-editor-23-others-make-sanwo-olus-list-of-commissioners-special-advisers.html.
- ↑ "Lagos Assembly committee completes screening of 25 cabinet nominees". Premium Times. 2019-08-03. https://www.premiumtimesng.com/regional/ssouth-west/344675-lagos-assembly-committee-completes-screening-of-25-cabinet-nominees.html.
- ↑ "Sanwo-Olu Assigns Portfolios To Commissioners, Others". Sahara Reporters (New York City, United States). 2019-08-20. http://saharareporters.com/2019/08/20/sanwo-olu-assigns-portfolios-commissioners-others.
- ↑ "Hope rises for Lagosians over Sanwo-Olu's cabinet". The Guardian (Lagos, Nigeria). Archived on 2019-08-26. Error: If you specify
|archivedate=, you must also specify|archiveurl=. https://guardian.ng/politics/hope-rises-for-lagosians-over-sanwo-olus-cabinet/.