Ọjọ́ àwọn Ọmọdé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Children's Day)
Àjọ Wikipedia tó ń ṣàjọyọ̀ ọjọ́ àwọn ọmọdé

Ọjọ́ àwọn Ọmọdé je ojo ti a ya soto lodoodun lati se ajoyo eye fun awon omode lagbaye. Ojo na yato lati orilede si orile-ede.

Ni odun 1925, Ojo awon Omode Kaakiriaye (International Children's Day) koko je yiyasile ni ilu Geneva nigba Ipade Agbaye fun Itoju Omode (World Conference on Child Welfare); lati igbana, won ti nsajodun ni June 1 ni awon orile-ede pupo. Ajo UN unsajodun ojo awon omode ni November 20.[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]