Clint Eastwood
Appearance
Clint Eastwood | |
---|---|
Eastwood ní Toronto International Film Festival ti ọdún 2010 | |
Ọjọ́ìbí | Clinton Eastwood, Jr. 31 Oṣù Kàrún 1930 San Francisco, California, U.S. |
Orílẹ̀-èdè | American |
Iṣẹ́ | Actor, director, producer, and composer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1955–present |
Olólùfẹ́ | Maggie Johnson (1953–84; two children) Dina Ruiz (1996–present; one child) |
Àwọn ọmọ | Kimber Tunis Kyle Eastwood Alison Eastwood Scott Reeves Kathryn Reeves Francesca Fisher-Eastwood Morgan Eastwood |
Clinton "Clint" Eastwood, Jr. (ọjọ́-ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kànlélógbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1930) jẹ́ òṣeré, olùdarí fíìmù, atọ́kùn àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |