Akọ̀wé-Àgbà Àjọni àwọn Orílẹ̀-èdè
Appearance
(Àtúnjúwe láti Commonwealth Secretary-General)
Akowe-Agba Ajoni awon Orile-ede ni olori Ile-ise Akowe Ajoni awon Orile-ede, akorajo gbogbogbo to n sise fun egbe Ajoni awon Orile-ede lati igba idasile re ni odun 1965 to ni ojuse fun sisoju Ajoni ni igboro.[1] Akowe-Agba Ajoni awon Orile-ede yato si Olori Ajoni awon Orile-ede, to je Queen Elizabeth II lowolowo.
Akojo awon Akowe-Agba
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oruko | Orile-ede | Ojoibi | Ojoalaisi | Bere | Pari | |
---|---|---|---|---|---|---|
1st | Arnold Smith | Canada | 18 January 1915 | 7 February 1994 | 1 July 1965 | 30 June 1975 |
2nd | Sir Shridath Ramphal | Guyana | 3 October 1928 | Living | 1 July 1975 | 30 June 1990 |
3rd | Chief Emeka Anyaoku | Nigeria | 18 January 1933 | Living | 1 July 1990 | 31 March 2000 |
4th | Sir Don McKinnon | New Zealand | 27 February 1939 | Living | 1 April 2000 | 31 March 2008 |
5th | Kamalesh Sharma | India | 30 September 1941 | Living | 1 April 2008 | Incumbent |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Role of the Secretary-General". Commonwealth Secretariat. Retrieved 2008-04-05.