Dayo Okeniyi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Dayọ Òkéníyì)
Dayọ̀ Òkéníyì
Ọjọ́ìbíOladayo A. Okeniyi
Oṣù Kẹfà 14, 1988 (1988-06-14) (ọmọ ọdún 35)
Jos, Nàìjíríà
Iṣẹ́Òṣèré orí-ìtàgé
Ìgbà iṣẹ́2010–present
HeightÀdàkọ:Infobox person/height

Ọládayọ̀ A. Òkéníyì tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìnlá oṣù Kẹfà ọdún 1988, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti àti sinimá ọmọ oeílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Òun ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Tresh látàrí ipa rẹ̀ tí.ó kó nínú eré 'The Hunger Games'.[1] [2] Òun náà tún ni ẹ̀dá ìtàn and Danny Dyson nínú eré Terminator Genisys.[3]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Dayọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Jos lóòtọ́, àmọ́ ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Èkó pẹ̀lú àwọn àbúrò mẹ́rin lẹ́yìn rẹ̀.[4] Bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ fèyìnti láti ilé-iṣẹ́ aṣọ́bodè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àmọ́ tí ìyá rẹ̀ jẹ́ olùkọ́ lítíréṣọ̀ láti orílẹ̀-èdè Kenya.[5] Òun àti àwọn ẹbí rẹ̀ kó kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ sí ìlú Indiana ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, kí wọ́n tún tó kó lọ sí California ní orílẹ̀-èdè.Amẹ́ríkà bákan náà. [1] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ̀kọ́ nínú ìmọ̀ visual communications ní ilé-ẹ̀kọ́ Anderson University (Indiana) ní ọdún 2009.[6] Ṣáájú kí ó tó kópa nínú eré The Hunger Games, Òkéníyì ti ṣiṣẹ́ ní àwọn sinimá ẹsẹ̀-kùkú àti yíya eré ìtàgé. [7] Òkénìyì bẹ̀rẹ̀ sí ń fara hàn nínú àwọn eré oníṣẹ́ bíi: Endless Love, tí ó sì tú kópa nínú eré Terminator Genisys ní ọdún 2015 gẹ́gẹ́ bí Danny Dyson. [8] Ó sì tún ti kópa nínú àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọkan eré NBC bíi Shades of Blue.

Àwọn àṣàyàn fíímù rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Fíìmù Ipa tí ó kó Notes
2011 Eyes to See Unknown role Short film
2011 Lions Among Men Tau Short film
2012 The Hunger Games Thresh
2012 The World Is Watching: Making the Hunger Games Himself
2013 The Spectacular Now Marcus
2013 Runner, Runner Perdeep
2013 Cavemen Andre
2013 Revolution Alec TV show
2014 Endless Love Mace
2015 Terminator Genisys Danny Dyson
2016 Good Kids Conch
2016–2018 Shades of Blue Michael Loman Series regular
2020 Run Sweetheart Run

Àwọn amì-ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Won[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Àdàkọ:Film-actor-stub Àdàkọ:Nigeria-actor-stub Àdàkọ:American-actor-stub