Devilert Arsene Kimbembe
Ìrísí
Devillert Arsene Kimbembe (tí wọ́n bí ní ọdún 1984 ní Brazzaville )[1] jẹ́ asáré eléré ìje ọmọ orílẹ̀ èdè Kóngò [2] Ó kópa nínú ìdíje ti òní 100m ti àwọn ọkùnrin ní Olympic Summer Olympics ti ọdún 2012 níbi tí ó ti yẹ ní ìpele àkọ́kọ́ pẹ̀lú àkókò tí ó dára jùlọ tí ó jẹ́ ìṣẹ́jú-àáyá 10.68 ṣùgbọ́n tí ó já kúrò ní ìpele àkọ́kọ́.
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Devilert Arsene Kimbembe Archived 2015-09-25 at the Wayback Machine.. Sports Reference. Retrieved on 2015-02-01.
- ↑ "Devilert Arsene Kimbembe". 2012 Summer Olympics. Archived from the original on 20 May 2013. Retrieved 11 September 2012. Unknown parameter
|url-status=ignored (help)