Jump to content

Diepreye Alamieyeseigha

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Diepreye Solomon Peter Alamieyeseigha
Diepreye Alamieyeseigha (right) with U.S. Ambassador to Nigeria Howard F. Jeter (left), July 6, 2001
Governor of Bayelsa State
In office
29 May 1999 – 9 December 2005
AsíwájúPaul Obi
Arọ́pòGoodluck Jonathan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí16 November, 1952
Amassoma, Bayelsa State, Nigeria

Diepreye Solomon Peter Alamieyeseigha ("DSP") (tí a bí ní ọjọ́ kerìndínlógún oṣù kọkànlá, ọdún 1952) je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Bayelsa télèrí. Ní oṣù kejì ọdún 2023, orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà fọwọ́ sí àdéhùn pẹ̀lú Nàìjíríà fún ìdápadà nǹkan bíi mílíọ̀nù kan dọ́là tí Deprieye Alamieyeseigha ti kó jẹ[1].



  1. Dregnounou, Laetitia Lago (2023-02-17). "Les USA restituent des fonds détournés par un ancien gouverneur nigérian". Africanews (in Èdè Faransé). Retrieved 2023-02-17.