Dieudonné Kwizera
Ìrísí
Dieudonné Kwizera (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹjọ ọdún 1967) jẹ́ asáré orí páápá ọmọ ilẹ̀ Burundi tí ó ti fẹ̀yìntì tí ó sì jẹ́ ògbóǹtarìgí nínú ìdíje oní 800 mítà .
Ní ọdún 1987, ó gba àmì-ẹ̀yẹ idẹ nínú ìdíje All-Africa Games ní Nairobi, ní ọdún tó tẹ̀lé e, ó parí ní ipò kẹta nínú ìdíje IAAF Grand Prix Final lẹ́yìn Tom McKean àti Sebastian Coe, àwọn méjèèjì láti ọrílé-èdè Great Britain.
Eré ìdíje ni Àgbáyé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]| 1987 | All-Africa Games | Nairobi, Kenya | 3rd | 800 m | 1:46.69 |