Doyin Okupe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Dr.
Doyin Okupe
Ọjọ́ìbíAdedoyin Ajibike Okupe
22 Oṣù Kẹta 1952 (1952-03-22) (ọmọ ọdún 72)
Iperu, Ogun State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Igbobi College and
University of Ibadan
Iṣẹ́Physician and Politician
OrganizationRoyal Cross Medical Centre
Gbajúmọ̀ fúnCo-founder of Royal Cross Medical Centre, National Publicity Secretary of NRC, Special Assistant to President Olusegun Obasanjo and Senior Special Assistant to President Goodluck Jonathan
Political partyPDP
(Past: NPN, NRC, UNCP, and Accord Party)
Olólùfẹ́Aduralere Okupe
Àwọn ọmọDitan Okupe
Parent(s)
  • Chief Matthew Adekoya Okupe (father)
Àwọn olùbátanBrothers: Kunle Okupe, Owo Okupe, Wemi Okupe and Larry Okupe
Sisters: Aina Okanlawon and Bisola Ayeni

Adédoyin Ajíbíkẹ́ Òkúpè tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù Kẹ́ta, ọdún 1952, tí a tún mọ̀ sí Dokita Doyin Òkúpè, jẹ́ dókítà àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̣̀-èdè Nàìjíríà kan ti o ṣe agbekalẹ Ile-iṣẹ ipoogun ti ''Royal Cross'' [1] [2] . pe o jẹ akọwe ikede ti Orilẹ-ede ti National Republican Convention (NRC) ). [3] [4] Ó wà lára àwọn tí Ọ̀gágun Sani Abacha tì mọ́lé nígbà ìṣèjoba rẹ̀ ti won si ja kuro lara awon adije-dupo iselu labele labe egbe oselu ''United Nigeria Congress Party'' (UNCP) [5] nigbamii, Doyin tun jẹ́ adije-dupo Gomina ni abe egbe òṣèlú People's Democratic Party (PDP) ní Ìpínlẹ̀ Ògùn. [6] [7] [8]

Ìgbà èwe rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Doyin ní ọjọ́ Kejìlélógún oṣù Kẹ́ta, ọdún 1952, ní ìlú Ìpẹru ní Ìpínlẹ̀ Ògùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [9] [10] Doyin jẹ ọmọ bibi Oloye Matthew Adékọ̀yà Òkúpè, ẹniti o jẹ osise Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà . Doyin lọ si ile-eko ti St. Jude ti o wa ni ilu Èbúté Méta, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, O tun kawe ni ile-eko ti Igbobi College ni ilu Yábàá, ti o si lo sile-eko Yunifásitì ti ÌbàdànÌlú Ìbàdàn, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ .

Iṣẹ́ òòjọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bi o tilẹ jẹ pe Okupe jẹ dokita onimo ìpoògùn, ba kan naa ni o tun n kopa ninu iṣelu pelu. [1] [2] [10] O jẹ olootu fun iwe-iroyin ilera kan ti oruke re n je ''Mirror'' nigba kan ri. [9]

iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ ìpoògù̀n[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Doyin sise ni ile-ise iwosan ijoba ati Ile-iwosan aladani, ti o fi mo ile-iwosan ti St. Nicholas Hospital, tí ó wà ní ìlú Èkó ṣáájú kí òun àti àwon akẹgbẹ́ rẹ̀ bíi: Dókítà Ṣe yí Roberts àti Dókítà Ládi Òkúbóyèjọ tí oruko re n je o to da ile-iwosan tire ti o pe ni ''Royal Cross Medical Centre'' ti a tun n pe ni (Royal Cross Hospital) ti o wà ní ìlú Ọbáléndé ní Ìpínlẹ̀ Èkó .[1] Nígbà tí ó jẹ́ alààyè àti adarí ilé-ìwòsan náà.[9]

Gónìnà àná tẹ́lẹ̀ rí ní Ìpínlẹ̀ Ògùn Olóyè Olúṣẹ́gun Ọ̀ṣọbà fìdí rẹ̀ múlẹ̀ nínú ìfọ̀rọ̀wáni-lẹ́nu wò kan tí ó wáyé pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn The Nation (Nigeria), nínú oṣù Keje ọdún 2019, wípé '' Dókítà Doyin Òkúpè àti akẹgbẹ́ rẹ̀ Dókítà Ṣèyí Roberts ni wọ́n dóòlà èmí aṣọ́gbà mi kan lọ́wọ́ ikú ọta Ìbọn tí ó bàá ní orí ní ọjọ́ Kẹtalélógún oṣù Keje ọdún 1994''.[2]

Ṣíṣe Ìṣèlú rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní àsìkò Ìṣèjọba alágbára ẹlẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Òkúpè jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú-àárín àgbà ní abẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú National Party of Nigeria (NPN) nínú Ìdìbò ọdún 1983.

Doyin ni ó jẹ́ alukoro àgbà fún ẹgbẹ́ òṣèlú National Republican Convention I, ìyẹn ní inú ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kẹta iru rẹ̀.[3] Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn aṣojú tí ẹgbẹ́ òṣèlú rẹ̀ yàn láti wà níbi ìkàbò Ààrẹ nílé ìbò National Electoral Commission (NEC) ní ọdún 1993.[4]

Doyin tún jẹ́ òkan lára àwọn tí Ọ̀gágun Sani Abacha tì mọ́lé nígbà ìṣèjoba rẹ̀ ní ọjọ́ Kẹta oṣù Kẹwàá ọdún 1996 ti won si ja kuro lara awon adije-dupo iselu labele labe egbe oselu ''United Nigeria Congress Party'' (UNCP)

..[5]

Ààrẹ Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ yan Doyin sí ipò igbákejì alukoro àgbà lórí ètò ìròyìn fún ìṣèjọba rẹ̀ .[3][11] Ní ọdún

200ó ìdíje dupò gómìnà ní abẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP nínú ìdìbò abẹ́lé ẹgbẹ́ wọn, amọ́ oyè náà já mọ́ th Gbenga Dan lọwọ́iel.[7] Ààrẹ Goodluck Jonathan yan Òkúpè gẹ́gẹ́ bí Olùràn lọ́wọ́ pàtàkì lórí ọ̀rọ̀ iṣẹ́ òde ní ọdún 2012.[6][8][12]

Okupe jẹ olùpolongo àgbà fún ẹgbẹ́ òṣèlú PDP pàá pàá jọ sí gbogbo àwọn olùdíje sí ipò Ààrẹ ní abè ẹgbẹ́ òṣèlú rẹ̀ láti orí ni Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́, Goodluck Jonathan , Bukola Saraki àti Atiku Abubakar . [3] [13] Ó kéde èrò ọkàn rẹ̀ láti kúrò nínú ẹgbẹ́ PDP kí ó sì dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ìṣèlú Accord ní ọdún 2017. Ẹgbẹ́ òṣèlú Accord le kúrò nínú ẹgbẹ́ òṣèlú wọn ní ọdún 2018, látàrí wípé ó gbà láti ṣe alukoro àti olùpolongo ìbò fún olùdíje sípò Ààrẹ lábẹ́ ẹgbẹ́ẹ́ òṣèlú PDP, ìyẹn Bùkọ́lá Sàrakí ní ọdún 2018. Ó padà sínú ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP tí ó sì jẹ́ agbẹnusọ àgbà fún olùdíje sípò ààr3 àyà Atiku Abubakar ní ọdún 2019. [14] [15] [16]

Ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Dayọ̀ Òkúpè fẹ́ ìyàwó rẹ̀ Aduralere Òkúpè. [17] wọ́n sì bí ọmọ ọkùnrin kan Ditan Okupe. [18]

Ní àkókò ìdìbò gbogbogbo ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2019, Dayọ̀ ṣe atìlẹ́yìn fún Atiku Abubakar tí ó jẹ́ adíje-dupò lábẹ́ ẹgbẹ́ẹ́ òṣèlú PDP, nígbà tí Ditan ọmọ rẹ̀ ṣe àtìlẹ́yìn fún Muhammadu Buhari . [18]

Nínú oṣù Karùn-ún ọdún 2020, wọ́n fi lèdè.wípé ìyàwó Dayọ̀ Òkúpè tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Aduralere kò àrùn COVID-19 ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin ọdún 2020. [17] [19] [20]

Rògbòdìyàn àti ìjẹ́jọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní inú oṣù Kẹjọ ọdún 2012, àjọ EFCC fi ẹ̀sùn kan Doyin wípé ní ọdún 2004 ó kùnà láti iṣẹ́ ọ̀nà tí Ipinle Imo gbé láti ṣe ní Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé . [21] Oun àti ìjọba Ìpínlẹ̀ Imo yanjú ọ̀rọ̀ náà ní ilé-ẹjọ́. [22]

Ní inú oṣù Keje ọdún 2016, wọ́n fi ẹ̀sùn kan Doyin wípé ó gba ₦ 702 mílíọ́nù nínú bílíọ́nù méjì ($ 2 bilionu) tí Dasuki kò jẹ. [23] [24]. [13]

Àwọn Itọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 Edward A. Gargan (15 October 1985). "For Nigerian Doctors, the Healing is the Easy Part". The New York Times. https://www.nytimes.com/1985/10/15/world/for-nigerian-doctors-the-healing-is-the-easy-part.html?searchResultPosition=2. 
  2. 2.0 2.1 2.2 "How I escaped assassination four times, by Osoba". 2 July 2019. https://thenationonlineng.net/how-i-escaped-assassination-four-times-by-osoba/. 
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 Abisola Olasupo (11 September 2018). "Saraki appoints Doyin Okupe head of Campaign media council". https://guardian.ng/news/saraki-appoints-doyin-okupe-head-of-campaign-media-council/. 
  4. 4.0 4.1 Humphrey Nwosu (1 August 2017). Laying the Foundation for Nigeria's Democracy: My Account of June 12, 1993 Presidential Election and Its Annulment. https://books.google.com/books?id=JQgvDwAAQBAJ&pg=PT276&lpg=PT276&dq=NRC+publicity+secretary+%22Doyin+Okupe%22#v=onepage. Retrieved 25 May 2020. 
  5. 5.0 5.1 Olusegun Adeniyi. The Last 100 Days of Abacha. https://books.google.com/books?id=j6cuAQAAIAAJ. Retrieved 25 May 2020. 
  6. 6.0 6.1 "Jonathan Appoints Okupe Aide". ThisDay Live. 27 July 2012. Archived from the original on 26 April 2014. https://web.archive.org/web/20140426201055/http://www.thisdaylive.com/articles/jonathan-appoints-okupe-aide/120938/. 
  7. 7.0 7.1 Chris Anucha (9 July 2002). "Okupe's Group Leads in Ogun PDP Primaries". https://allafrica.com/stories/200207090434.html. 
  8. 8.0 8.1 "Okupe appointed Jonathan's adviser". Punch Newspaper. 27 July 2012. Archived from the original on 26 April 2014. https://web.archive.org/web/20140426214756/http://www.punchng.com/news/okupe-appointed-jonathans-adviser/. 
  9. 9.0 9.1 9.2 Gbenga Akinfenwa (17 March 2019). "Birthdays". https://www.pressreader.com/nigeria/the-guardian-nigeria/20190317/282303911465286. 
  10. 10.0 10.1 Femi Salako (22 March 2018). "Tribute to a doyen of patriotism". Archived from the original on 22 March 2018. https://web.archive.org/web/20180322024826/https://www.dailytrust.com.ng/tribute-to-a-doyen-of-patriotism.html. 
  11. Tony Orilade (31 January 2000). "Obasanjo Begins His Tour of Niger State". TheNews (Nigeria). https://allafrica.com/stories/200001310265.html. 
  12. "Jonathan appoints Okupe SSA Public Affairs". http://dailyindependentnig.com/2012/07/jonathan-appoints-okupe-ssa-public-affairs/. 
  13. 13.0 13.1 Chinedu Asadu (14 January 2019). "EFCC arraigns Okupe for 'N702m fraud'". TheCable. https://www.thecable.ng/just-in-efcc-arraigns-okupe-for-n702m-fraud. 
  14. Fredrick Nwabufo (18 July 2017). "Okupe joins Accord party, says he is not desperate to be anything". TheCable. https://web.thecable.ng/okupe-joins-accord-party-says-not-desperate-anything. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  15. Chijioke Jannah (13 September 2018). "Accord party expels Doyin Okupe, gives reason". Daily Post (Nigeria). https://dailypost.ng/2018/09/13/accord-party-expels-doyin-okupe-gives-reason/. 
  16. Fikayo Olowolagba (11 November 2018). "2019 Presidency: Why I returned to PDP – Doyin Okupe". Daily Post (Nigeria). https://dailypost.ng/2018/11/11/2019-presidency-returned-pdp-doyin-okupe/. 
  17. 17.0 17.1 Ebunoluwa Olafusi (12 May 2020). "Okupe: My wife and I have recovered from COVID-19". TheCable. https://www.thecable.ng/okupe-my-wife-and-i-have-recovered-from-covid-19. 
  18. 18.0 18.1 Lanre Babalola (9 November 2018). "Doyin Okupe's son joins Obasanjo's son to support Buhari". TheNews (Nigeria). https://www.pmnewsnigeria.com/2018/11/09/doyin-okupes-son-joins-obasanjos-son-to-support-buhari/. 
  19. "Ex-presidential aide, Doyin Okupe, wife now negative after testing positive for coronavirus". Nigerian Tribune. 12 May 2020. https://tribuneonlineng.com/ex-presidential-aide-doyin-okupe-wife-now-negative-after-testing-positive-for-coronavirus/. 
  20. "Former Presidential Spokesperson, Doyin Okupe, Wife Discharged From COVID-19 Isolation Centre After Testing Negative". Sahara Reporters. 12 May 2020. http://saharareporters.com/2020/05/12/former-presidential-spokesperson-doyin-okupe-wife-discharged-covid-19-isolation-centre. 
  21. "PDP, ACN bicker over Okupe". 21 August 2012. http://www.vanguardngr.com/2012/08/pdp-acn-bicker-over-okupe/. 
  22. "Okupe Lawyers Admit He Did Fraudulent Contracts With Imo And Benue". Sahara Reporters. 21 August 2012. http://saharareporters.com/2012/08/21/okupe-lawyers-admit-he-did-fraudulent-contracts-imo-and-benue. 
  23. Henry Umoru (18 July 2016). "What I did with Dasuki's money – Okupe". Vanguard Newspaper. https://www.vanguardngr.com/2016/07/okupe-explains-nsa-paid/. 
  24. Kunle Sanni (26 June 2019). "N702m Dasukigate: EFCC closes case against Okupe". Premium Times. https://www.premiumtimesng.com/news/more-news/337292-n702m-dasukigate-efcc-closes-case-against-okupe.html. 

Ẹ kà siwájú si[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Igbesiaye ti Doyin Okupe

Okupe, Doyin (2017). "2019 kuru ju lati yi Nigeria pada - Doyin Okupe". Iwe iroyin Vanguard Nigeria .

Salako, Femi (2018). Archived 2018-03-22 at the Wayback Machine. "Oriyin si doyen ti orilẹ-ede-ilu". Archived 2018-03-22 at the Wayback Machine. Iwe iroyin Dailytrus Archived 2018-03-22 at the Wayback Machine.