Jump to content

Dundun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Dundun

  • Akin Euba (1990), Yoruba Drumming: The Dundun Tradition. Bayreuth: Eckard Breitinger. ISBN 3-927510-11-4; ISSN: 0178=0034. Oju-iwe = 434.

Oro nipa dundun ti o je ilu kan pataki ni ile Yoruba ni onkowe yii soro le lori. O menu ba ipo dundun ninu asa Yoruba, itan ti o je mo dundun, ibi ti a ti maa n lo o ti o si fi ibi aseye kan se apeere. O soro nipa bi won sen se e ati awon ilu miiran ti won maa n lu mo on. Aworan po ninu iwe naa. Ami ti awon onitilutifon maa n lo fun orin naa wa ninu re pelu.