Ebiti Ndok
Ebiti Ndok | |
---|---|
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ebiti Onoyom Ndok Ibadan, Oyo State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | United National Party for Development (UNPD) |
Àwọn ọmọ | 4 |
Alma mater | University College Hospital, Ibadan St Anne's School Ibadan |
Occupation | Politician |
Profession | Nurse |
Ebiti Ndok-Jegede jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà . Ó díje dùn ipò ààrẹ nínú ìdìbò tó wáyé ní ọdun 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú United National Party for Development.
Ètò ayé àti iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]́Wońgẹ́íbí alága badan tí olú ìlú rẹ̀ jẹ́ Ìpínlẹ̀ Ọ̀yó South-Western Nàìjíríà , Ndok-Jegede je ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, ní orílè-èdèNàìjíríà. [1] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ St Anne ní ìlú Ìbàdàn fún ẹ̀kọ́ girama. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ nọ́ọ̀sì ní ilé ìwòsàn Yunifásítì ti ìlú Ìbàdàn kó tó lọ sí ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, níbi tó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ètò ìṣàkóso, òfin àti diplomacy, tó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ nípa iṣẹ́ alámòójútó. [2] Ni ọdun 2011, òun nìkan ni obìnrin tó díje dun ipò aarẹ Naijiria lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú United National Party for Development, ó sì ní ìbò 98,262. [3] [4] [5]
Igbesi aye ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ndok-Jegede ti ni ọkọ pẹlu ọmọ mẹrin.
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ http://allafrica.com/stories/201105241166.html
- ↑ http://myafrica.allafrica.com/view/people/main/id/0CQvFWXfcXGIXrKQ.html
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2016-09-19. Retrieved 2025-06-21.
- ↑ https://web.archive.org/web/20170117110617/http://leadership.ng/features/373288/2015-female-politicians
- ↑ https://web.archive.org/web/20160918023747/http://m.mgafrica.com/article/2015-04-13-fortunes-of-women-presidential-candidates