Egungun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

EGUNGUN

Paleopathology; Human femurs from Roman period, Tell Fara Wellcome L0008764.jpg

egungun je okan pataki ninu awon Orisa akunlebo ni ile Yoruba. Egungun ni a tun mo si ara orun, awon Yoruba gbagbo pe nigba ti egun ba jade pe oku orun lo wa lati wa ba awon eyan re pejo, lati wa ba araye jiroro. Eegun je Orisa kan to ma n fi aso Bo gbogbo ara, aso yii si la mo si eku tabi agò. Nigbakugba ti egungun ba ma jade, oru ayajo ojo yii ma n je ojo ayeye nla, o ma je ojo idunu ati ojo irawo ebe si awon oku orun tori awon Yoruba gbogbo pe omo ina la n ran si ina leyi to tumo si pe oku la n ran so oku ti yio si le Jise ni kiakia. Awon Yoruba a ma fun egun lebu won a si ma tara rawo ebe si olorun fun ohun rere kan tabi omiran.[1]won Awo tabi awon ti o ni igbagbo tabi ti won my egungun sise ni okunkundun ni awon ti a no si awon Oloje, awon won yii lo n Se ki Kari ni won so no pupo ni pa asiri eegun.[2] Die lara awon oloye eegun ni: Alaagba Iyamoje Atokun egungun Bojuto Apena Iya agon abbl. O je okan pataki lara ewo oro; a ki I foko ko le nigbale, omiran tun ni pe eegun o gbodo te fuku agbado mole, atiwipe bi eegun ba n padan lowo ojo o gbodo ro ba. Atokunrin atobinrin lo n sawo egungun. Osan gangan si ni eegun ma n jade. Awon elegun won ma n padan lorisiirisii.

Egungun je Orisa kan ni ile Yoruba ti a n bo lati ri aanu, ojurere, omo, iyawo tabi ohun ti a ba fe gba. 


Orisiirisii ni eegun ti a ni won oruko won so yato lati adugbo kan si omiran. A ni awon eegun Alagbada; awon won Yi ni eegun to ma n yi aso. A ni eegun ti a mo si eegun Ajofoyinba;eegun yii lo ma n pesa, a ni eegun Alaago; awon eegun won yii je eegun oni faaji, ati awon eegun Miran to yato lati Ilu kan si omiran.

ITAN TO RO MO EGUNGUN

Onirunrun itan lo ro mo Iwasayi tabi ibere egungun sugbon eyi ti a o salaye ni Itan akoni ti a mo si Ogogo omo kulodo. 

Ogogo omo kulodo je akinkanju jagunjagun ni Ilu Oyo, no ojo kan iro kan Alaafin Oyo leti pe awon kan n kogun Bo lati wa ba Ilu Oyo, kin ni Alaafin gbo yii si ni o yara ke si Ogogo jagunjagun lati wa lo koju awon ota sebi koju ma ribi gbogbo ara bayi logun e. Nigba ti Ogogo omo kulodo doju ogun o ja ajasegun o Segun ota o reyin odi, bi o Se fe ma pada sile isele buruku kan se! Okan ninu awon ota won ni o moribo ninu iku ojona ti o si pawoda to tun Awo Se lo ba mu kini kan jade lati inu apo e loba fi meji kun ookan lo sa a bi oloogun ti n gbe sa a Lo ba fe fife to fe kini ohun konge ara ku lodo lo se, ni kulodo o ba le sokunrin mo, Ogogo wa so fun awon omo ogun e pe ko lo so fun won Nile pe ohun Ogogo omo kulodo ti bogun lo ati wi pe ohun a ma yoju si won lorekore. Leyin odun kan Ogogo ranse si awon ara oyo pe ohun n Bo ki won gbalugbajo, ki no mura ati gba alejo ohun, o si tun so fun omo e pe ki o ran aso wa fun ohun, eyi ti yio boju buse ti ko si ni fi ago ara kankan sile. Ojo ti Ogogo da ohun pe awon ara Ilu Oyo n reti alejo to n bo, awon kan tile n seye meji pe bawo ni ara orun sele waye, Ogogo o de titi o fi dojoro nigba ti oorun ti pari Ise oojo e. Nigba ti Ogogo wolu ko si eni to RI Oju tabi nnkankan lara e sugbon ohun re je tan Omole si iru eni ti n be ninu eku. Ogogo si n se bayi ni ododun. Eyi je okan lara ITAN to ro mo iwasaye egungun. Ko fe e si Ilu kan ni ile Yoruba ti ko ni egungun.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. PublBishing, Argosy. "Types of Bones - Learn Skeleton Anatomy". Visible Body. Retrieved 2019-06-06. 
  2. "Bones, Muscles, and Joints (for Parents)". KidsHealth. Retrieved 2019-06-06.