Eku ti odò
Ìrísí

Eku ti odò ganganrangan (beaver)
Eku ti odò kékèré (water rat)
Boye e n béèré kini idi awa n pe won eku ti odò ganganrangan ati eku ti odò kékèré. Awa n so eku ti odò ganganrangan ati eku ti odò kékèré nitori okan ninu won je ganganrangan (o tobi) ati okan ninu won kékèré.
Eku ti odò ganganrangan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eku ti odò ganganrangan ni ehin ti o tobi gan, ehin re won ma hù kiakia, ati eku ti odò ganganrangan feran lati gé awon igi lati ko ilé won ninu omi. Àwon eku ti odò ganganrangan, won ni iru ti o gun.[1]
Eku ti odò kékèré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eku ti odò, won dẹ ati won n gbé ni odò dabi oruko re n so. Ati won n gbé ni odò sisan kekere ati adágún.[2] Eku ti odò kekeré, oju won je kekeré, ati won le pa iho imu won lati se pé, omi ko ma wole.