Ella Baker
Appearance
Ella Baker | |
---|---|
Àwòrán Ella Baker pẹ̀lú àgàsọ rẹ: | |
Ọjọ́ìbí | Ella Josephine Baker Oṣù Kejìlá 13, 1903 Norfolk, Virginia, USA |
Aláìsí | December 13, 1986 Manhattan, New York City, USA | (ọmọ ọdún 83)
Iléẹ̀kọ́ gíga | Shaw University |
Organization | NAACP (1938–1953) SCLC (1957–1960) SNCC (1960–1962) |
Movement | Civil Rights Movement |
Olólùfẹ́ | T.J. (Bob) Roberts, divorced 1958 |
Ella Josephine Baker (December 13, 1903 – December 13, 1986)[1] je Alawodudu ara Amerika to je alakitiyan eto araalu ati eto omoniyan ti a bi ni ipinle Virginia, sugbon to dagba ni ipinle North Carolina to si pari eko giga re nibe, o sise ni opo gbogbo ile-aye re ni ilu New York. O fibe sise leyin ago nibi to ti n se alagbajo fun bi ogorun odun. O sise legbe awon olori akitiyan eto araalu bi W. E. B. Du Bois, Thurgood Marshall, A. Philip Randolph, ati Martin Luther King, Jr. be sini o je atona fun Diane Nash, Stokely Carmichael, Rosa Parks, ati Bob Moses.[2]
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Neil A. Hamilton (14 May 2014). American Social Leaders and Activists. Infobase Publishing. pp. 28–. ISBN 978-1-4381-0808-7. https://books.google.com/books?id=tKxOpAh78IsC&pg=PA28.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedrobert