Jump to content

Emmanuel Olatunji Adesoye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Emmanuel Olatunji Adesoye
Ọjọ́ìbí25 April 1937
Offa, Nigeria, Kwara State
Aláìsí2017
Offa, Nigeria, Kwara State
Burial placeOffa, Nigeria, Kwara State
Ìgbà iṣẹ́1938-2007

Emmanuel Olatunji Adesoye OON, CON (tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1938 – 2017) jẹ́ onímọ̀ nípa ilé wiwon ní orílè-èdè Nàìjíríà, o jẹ gbajúmò oníṣòwò, o sì tún jẹ olóyè pẹ̀lú. Ó jẹ́ onímọ̀ nípa ilé wiwon ní aríwá orílè-èdè Nàìjíríà àti onímọ̀ nípa ile wiwon kejì ní orílè-èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 2006, Ààrẹ Olusegun Obasanjo fún un ní àmì ẹ̀yẹ OON (Olórí Ẹgbẹ́ ti Nàìjíríà ) àti CON (Olórí Ẹgbẹ́ ti Nàìjíríà).[1][2][3]

Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Emmanuel Adesoye sì ìdílé Adesoye ní oṣù kẹrin ọdún 1938 ní ìjọba ìbílè Offa, ní ìpínlẹ̀ Kwara, orílè-èdè Nàìjíríà.[4]

Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alakobere African Bethel School Ebute-Metta ní ìlú Èkó láàrín ọdún 1948 sí 1951 àti ilé-ẹ̀kọ́ St Marks ní ọdún 1952. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Offa Grammar School láàrín ọdún 1953 sí 1957 fún ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yaba ní ìlú Èkó ní ọdún 1958. Ó jáde ilé-ẹ̀kọ́ gíga Nigerian College of Arts, Science, àti Technology ní ìlú Enugu ní ọdún 1959. Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí South East College of Arts, Science, àti Technology ní orílè-èdè UK láàrín ọdún 1961 sí 1963.

Àwọn ẹ̀bùn àti ọlá

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adesoye jẹ ọmọ Ẹgbẹ́ onísirò ilẹ wiwọn ní ìlú London (1965); o jẹ onísirò ilẹ wiwọn àkọ́kọ́ ní Àríwá ilẹ Nàìjíríà ati onísirò ilẹ wiwọn keji ni ìlú Nàìjíríà. O jẹ ọmọ Ẹgbẹ́ Royal Institute of Chartered Quantity Surveyors (1968) ati ọmọ Ẹgbẹ́ Nigerian Institute of Chartered Quantity Surveyors (1985). Òun nì Ààrẹ Defunct Afribank (1987–1989). O sí di ipò Maye ti ìlú Offa mú ní ọdun (1979) àti pé Alayéluwa Ọba Mustapha Oláwóore Olanipekun, Olofa Kẹrinlelọgbọn fún ní Idalola.Ni ọdún 2001, wọn da lọla pẹlú oyè Asiwaju ti ìlú Offa lẹyìn ikú Asiwaju akọkọ Offa, Olóyè Josiah Sunday Olawoyin ní ọjọ kejidinlogbon oṣù kẹrin ní ọdun 2001 ti Tajudeen Owoyemi[5][1][6][7] si rọpo rẹ. O jẹ Oludasile Okin biscuit limited.[8]

O jẹ oniriri ati onísirò ilẹ wiwọn,ati pé o jẹ Olùdásílẹ̀ ati Olùdarí ilé-ìwé Adesoye College Offa.[9][10][11]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1 2 Opinion (2021-10-30). "Asiwaju of Offa: Who the cap fits?" (in en-US). The Punch. https://punchng.com/asiwaju-of-offa-who-the-cap-fits/.
  2. ↑ "Chief Emmanuel Olatunji Adesoye (OON, CON) – DAWN Commission" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-11-09.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. ↑ "Chief Emmanuel Olatunji Adesoye Archives". The Eagle Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2024-11-10. Retrieved 2024-11-10.
  4. ↑ "Saraki, Gov Ahmed, ODU, others mourn foremost industrialist, Adesoye". National Pilot Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-11-10.
  5. ↑ Ajagunna, Friday (2017-12-20). "Buhari commiserates with family of late industrialist, Chief Emmanuel Adesoye". New Mail Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-11-10.
  6. ↑ Udo, Mary (2016-12-08). "ADESOYE, Chief, Emmanuel Olatunji (OON, CON)". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-11-10.
  7. ↑ "Makanjuola: How Adesoye College Shaped My Life". This Day. https://www.thisdaylive.com/index.php/2024/06/29/makanjuola-how-adesoye-college-shaped-my-life/.
  8. ↑ Wande, S.-Davies (2018-01-23). "Awoist pays tribute to Offa industrialist" (in en-GB). Nigerian Tribune. https://tribuneonlineng.com/awoist-pays-tribute-to-offa-industrialist/.
  9. ↑ "Meet The Founder – Adesoye College Offa" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-11-10.
  10. ↑ "Adesoye's death, exit of a Colossus - Oluwasola, son". Vanguard (Lagos, Nigeria). 9 March 2018. https://www.vanguardngr.com/2018/03/adesoyes-death-exit-of-a-colossus-oluwasola-son/.
  11. ↑ "Saraki Mourns Late Adesoye". Vanguard (Lagos, Nigeria). 2024. https://www.vanguardngr.com/2017/12/saraki-mourns-late-adesoye/amp/#amp_ct=1731217859443&amp_tf=From%20%251%24s&aoh=17311667675772&referrer=https%3A%2F%2.