Jump to content

Enyinna Nwigwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Enyinna Nwigwe
Ọjọ́ìbíNgor Okpala
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Calabar
Iṣẹ́Actor, producer
Ìgbà iṣẹ́2005 - present

Enyinna Nwigwe jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ati olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni ó gbé àwọn aládùn bíi: The Wedding Party, Black November, àti Black Gold jáde.

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n tó Nwigwe ní ìlú Ngor Okpala ní Ìpínlẹ̀ Imo ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1] Ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ fásìtì ti ìlú CalabarÌpínlẹ̀ Delta nínú ìmọ̀ Ìṣúná. [2]

Nwigwe bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ lásìkò tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ módẹ́ẹ̀lì pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ runway àti print model ṣáájú kí ó tó darapọ̀ mó iṣẹ́ tíátà.[3] Ó gbé eré kan jáde tí ó pè ní Wheel of Change eré tí Jeta Amata darí rẹ̀ ní ọdún 2004. [4]Ní báyìí, Nwigwe ń lọ sí ìlú Los Angeles ati orílẹ̀-èdè Nigeria láti ṣíṣe rẹ̀. [5] Ó ti kópa nínú àwọn eré orísiríṣi ṣáájú kí ó tó kópa nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Black November tí àwọn òṣèré bíi Kim Basinger, Mickey Rourke, Vivica A. Fox, Akon, Wyclef Jean, and Anne Heche ti kópa ní ọdún.[6] Ó kópa bí olú-èdá ìtàn gẹ́gẹ́ bí páítọ̀ nínú eré Hell or High Water, ní ọdún 2015. Lẹ́yìn eré yí ni ó pinu láti máa kòpa nínú eré tí ó bá ti níṣe pẹ̀lú ìṣẹ̀lẹ̀ àwùjọ.[7][8] Ní ọdún 2017, News of Africa pèé ní Ẹni àkọ́kọ́ nínú àwọn méjìlá tí ojú wọn fani-mọ́ra jùlọ ní Nollywood, lọ́dún náà. [9]


Ọdún Àkọ́lé eré Ioa tí ó kó Àríwísí
2005 Wheel of Change Tony
Last Game Gubabi
2006 Games Men Play Attorney
The Amazing Grace Etukudo, Associate Producer
2011 Black Gold Tamuno, Co-Producer
2012 Turning Point Steve
Black November Tamuno Alaibe, Associate Producer
2015 Silver Rain Bruce
Love Struck Actor TV Movie
2016 Put a Ring on It Robert
Hell or High Water Actor Short Film
When Love Happens Again Enyinna
Dinner Adetunde George Jnr.
The Wedding Party Nonso Onwuka
2017 Hire A Man Jeff
Red Code Charles
Atlas Osas
The Wedding Party 2 Nonso
2019 Living in Bondage: Breaking Free Obinna Omego
2019 Cold Feet Tare
2020 Dear Affy Micheal

Àwọn eré orì amóhù-máwòrán

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó Àríwísí
2008 Mary Slessor Prince, Producer

[10]

Àwọn amì-ẹ̀yẹ ati ìfisọrí rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n yan Nwigwe amì-ẹ̀yẹ ti Nollywood and African Film Critics Award, ní ọdún 2015, ati òṣèré amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ African Oscars nínú eré Black November.[11] Ní ọdún 2016, wọ́n tún yàn án fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó peregedé jùlọ nínú eré Gẹ̀ẹ́sì níbi amì-ẹ̀yẹ City People Entertainment Awards.[12]

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "I Don’t Want To Be Another Actor – Enyinna Nwigwe" (in en-US). Top Celebrities Magazine. 2015-04-01. Archived from the original on 2017-08-01. https://web.archive.org/web/20170801154923/https://www.topcelebritiesng.com/i-dont-want-to-be-another-actor-enyinna-nwigwe/. 
  2. "Biography/Profile/History Of Nollywood actor Enyinna Nwigwe – Daily Media Nigeria". dailymedia.com.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-07-04. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "Enyinna Nwigwe – Runway model to award-winning actor" (in en-US). Archived from the original on 2017-06-30. https://web.archive.org/web/20170630031529/http://guardian.ng/life/spotlight/enyinna-nwigwe-runway-model-to-award-winning-actor/. 
  4. AsuquoE (2014-12-23). "Meet Enyinna Nwigwe - The talented and good-looking Nigerian born Nollywood Actor and Producer on an impressive climb to stardom". TalkMedia Africa. Retrieved 2017-07-05. 
  5. Izuzu, Chidumga. "Enyinna Nwigwe: Here"s everything you need to know about actor"s "unusual" character in "Suru L" ere"" (in en-US). Archived from the original on 2017-08-01. https://web.archive.org/web/20170801164447/http://www.pulse.ng/movies/enyinna-nwigwe-heres-everything-you-need-to-know-about-actors-unusual-character-in-suru-l-ere-id4608003.html. 
  6. Offiong, Adie Vanessa (March 4, 2017). "I want to win an Oscar –Enyinna Nwigwe". Daily Trust. Archived from the original on August 1, 2017. Retrieved July 4, 2017. 
  7. "Enyinna Nwigwe talks shooting gay scene with actor Daniel K Daniel - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games" (in en-GB). Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games. 2016-06-13. http://thenet.ng/2016/06/enyinna-nwigwe-talks-shooting-gay-scene-with-actor-daniel-k-daniel/. 
  8. "Enyinna Nwigwe, Daniel K. Daniel, and others give rousing performances in gay-themed movie, Hell or High Water » YNaija" (in en-GB). YNaija. 2017-03-31. https://ynaija.com/enyinna-nwigwe-daniel-k-daniel-others-give-rousing-performance-gay-themed-movie-hell-high-water/. 
  9. "Meet The 12 Sexiest Nollywood Actors in 2017 (Photos)" (in en-US). News of Africa - Online Entertainment - Gossip - Celebrity Newspaper - Breaking News. 2017-03-22. Archived from the original on 2018-02-17. https://web.archive.org/web/20180217041852/http://newsofafrica.org/205746.html. 
  10. "Enyinna Nwigwe". IMDb. Retrieved 2017-07-04. 
  11. Editor, The (2015-07-02). "Oprah Winfrey, Vivica Fox, RMD, AY & Others make Nollywood & African Film Critics’ Awards (NAFCA) Nominees List". Nollywood Observer. Retrieved 2017-07-04. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  12. Izuzu, Chidumga. "City People Entertainment Awards 2016: "Suru L"ere," "Tinsel," Adeniyi Johnson, Mide Martins among nominees" (in en-US). http://www.pulse.ng/movies/city-people-entertainment-awards-2016-suru-lere-tinsel-adeniyi-johnson-mide-martins-among-nominees-id5249079.html. 

Àdàkọ:Authority control