Erinmilókun
Ìrísí


Erinmilókun (hippopotamus) je eranko nla ti n gbé ninu omi. Ati o le saré pelu iyara ti ogbon kilomita ni wakati okan. Boya, o dabi pé eranko yii, ko le saré kiakia, sugbon iyara re je kiakia ju o po ninu awon eniyan. Enu ti erinmilókun gboro ati o tobi gan. Enu ti erinmilókun ni agbara ti o poju enu ti kiniun. Ti erinmilókun ba gbidanwọ lati ge-jẹ tabi bu-jẹ èniyàn, o ma ge ati be pẹlẹbẹ ara ti èniyàn ni apakan meji! E jo, e ma duro pèlú won, ojola won le pa èniyàn.[1]