Jump to content

Eucharia Okwunna

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Eucharia Okwunna
Ọjọ́ìbí3 November 1961
Aguata, Anambra State, Nigeria
Iṣẹ́Politician
Gbajúmọ̀ fúnMember of the Nigerian House of Representatives
Political partyPeople's Democratic Party
Àwọn ọmọ4

Eucharia Azodo Okwunna (ojoibi 3 Kọkànlá Oṣù 1961) jẹ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. O jẹ ọmọ ẹgbẹ òṣèlú People's Democratic Party to sójú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà. Lọ́dún 2015, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà mọ́kànlélógún.

Igbesi aye ati iṣẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdun 1961 ni a bí Okwunna. Wọ́n yàn án ní ọdún 2003, lẹ́yìn náà ni wọ́n tún yàn án lọ́dún 2007 [1] sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Anambra, níbí tí ó ti di ipò Agbẹnusọ. [2] Oun ni obìnrin akọkọ ti o di ipo ìdìbò yẹn mu. [1]

Okwunna wa ni ile ìgbìmò aṣofin kékeré fún ọdun mẹjọ ṣaaju ki o to pinnu lati díje fun Ile-igbimọ aṣòfin àgbà ni ọdun 2018, láti ṣoju Anambra South. O jẹ sẹnetọ fun ẹgbẹ òṣèlú peoples democratic party (PDP) ni ọdun 2019 ati ọkan ninu awọn obinrin mọkanlelogun ni ile igbimọ aṣofin Naijiria.

Igbesi aye ara ẹni

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Okwunna je ìyàwó si Betrand Azodo. [3] Wọn ni bi ọmọ mẹrin, ati pe o jẹ ìyà àgbà. [3]