Eunice Idausa
Ìrísí
| Òrọ̀ ẹni | |
|---|---|
| Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
| Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹjọ 1975 |
| Sport | |
| Erẹ́ìdárayá | Handball |
Eunice Idausa (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1975) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù Olọ́wọ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin ní Olimpiiki Ìgbà Òjò ti ọdún 1992.[1]