F.C. Ashdod
Ìrísí
| Fáìlì:FC Ashdod.svg | ||||
| Full name | Moadon Sport Ashdod | |||
|---|---|---|---|---|
| Nickname(s) | הדולפינים (The Dolphins) הקבוצה מעיר הנמל (The Port City Team) | |||
| Founded | 1999 | |||
| Ground | Yud-Alef Stadium, Ashdod (Capacity: 7,800) | |||
| Owner | M.S. Ashdod Supporters trust | |||
| Chairman | Rafi Niddam | |||
| League | Àdàkọ:Israeli football updater | |||
| Àdàkọ:Israeli football updater | Àdàkọ:Israeli football updater | |||
| Website | [fcashdod.co.il Club home page] | |||
| ||||
Moadon Sport Ashdod (מועדון ספורט אשדוד), tí a sábà ń pè ní F.C. Ashdod (מ.ס. אשדוד), jẹ́ ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù-aláfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Ísírẹ́ẹ́lì, tó ń gbá bọ́ọ̀lù ní agbègbè òkun ni ilu Ashdod. Orúkọ ẹgbẹ́ náà, lèyí tó ṣe bé yàtọ̀ ( sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù bọ́ọ̀lù-aláfẹsẹ̀gbá Ísírẹ́ẹ́lì, latari bí kò ṣe sí bí àmì àjọṣepọ̀ tí ó tọ́ka won gẹgẹbi egbe agbábóòlù Júù kan pàtó bí Hapoel, Maccabi, tàbí Beitar,ó lọ wáyé látàrí ìjà orogun tí òun be láàárín ikò agbábóòlù Hapoel Ashdod àti Maccabi Ironi Ashdod ní ọdún 1999. Ẹgbẹ́ Agbábóòlù Ashdod ń kópa lọ́wọ́ nínú ìdíje Israeli Premier League.