Florence Aya
Florence Diya Aya | |
---|---|
Member, Kaduna State House of Assembly | |
In office 1990–1993 | |
Constituency | Kaura |
Member, House of Representatives | |
In office 1999–2003 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1948 Garkida |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Yohanna Aya |
Àwọn ọmọ | 5 |
Alma mater | Waka Girls Primary School, Government Girls College, Dalle |
Occupation | Politician, businesswoman |
Florence Diya Aya jẹ́ olúṣèlú àti oníṣòwò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n bi sí ìlú Garkida ní ọdún 1948, ó dẹ̀ wá láti Garaje Agban, Kagoro, ní ìjọba-ìbílẹ̀ Kaura Local ní ìpínlẹ̀ Kaduna.[1]ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ aṣòfin fún ìpínlẹ̀ Kaduna ní orílé-èdè Nàìjíríà láti 1990 sí 1993.
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aya lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ Waka Girls Primary School láàárín ọdún 1957 sí ọdún 1961. Ó tẹ̀ sí ní ilé ẹ̀kọ́ girama Government Girls College, Dalle, ní ìpínlẹ̀ Kano. Láàárín odún 1962 sí 1966, Ó ṣíṣe ní ilé ìkàwé (library) Kashim Ibrahim, ní fásitì Ahmadu Bello, láàárín ọdún 1963 sí ọdún 1969, àti akọ̀wé Agbo-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ Ẹ̀rọ ni fásitì Ahmadu Bello University ní Zaria láàárín ọdún 1972 sí ọdún 1984.Ó jẹ́ oníṣòwò bẹntiró tí ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé iṣẹ́ African bentiró láàárín ọdún 1984 sí ọdún 1989.[2]