Gana Abba Kimet
Ìrísí
Gana Abba Kimet (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún, ọdún 1946) jẹ́ Asáré orí páápá Eré ìje tó ń ṣojú fún orílẹ̀ èdè Chad ní àgbáyé.
Kimet ṣojú fún orílẹ̀ èdè Chad nínú àwọn ìdíje Olimpiiki Ìgbà Ẹ̀ẹ̀rùn ọdún 1972 ní Munich . Ó kópa nínú àwọn ìdíje 100 mítà ó sì parí ní ipò karùn-ún nínú eré ìdíje na , lèyí tí kò jẹ kò lè tẹ̀síwájú sí ìpele tó tẹ̀lé e.[1]
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Gana Abba Kimet profile". sports-reference.com. Sports Reference LLC. Archived from the original on 21 November 2015. Retrieved 22 November 2015. Unknown parameter
|url-status=ignored (help)