Gbémi Ọlátẹ́rù Ọlágbẹ́gi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Gbémi Ọlátẹ́rùỌlágbẹ́gi
Gbemi Olateru Olagbegi TGIF on NdaniTV 2019.png
in 2019
Iṣẹ́Media consultant, Television show host and radio personality
Ìgbà iṣẹ́2008–present
Àwọn olùbátanBukunyi Olateru-Olagbegi

Gbémi Ọlátẹ́ Ọlágbẹ́gi jẹ́ akàròyìn, atọ́kù ètò lórí ìkànì rédíò Cool FM àti The Beat 99.9 FM ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1][2][3] Ó gba ẹ̀bùn ìdánilọ́lá ti Future Award ti ọdún 2008 fún àwọn ètò rẹ̀ lórí afẹ́fẹ́, bákan náà ní ọdún 2009 ó ṣe agbátẹrù ètò àmì ayẹyẹ Future Award yí kan náà pẹ̀lú àwọn won gbajúmọ̀ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ (on-air personality) mọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. of the year at the 2008 Future adẹ́rìín-pòṣónú Jedidah.[4][5][6][7] Ẹ̀wẹ̀, ó tún jẹ́ celebrity model fún ìparun (Soul Mate hair products).[8] Bákan náà ó sì tún jẹ́ adarí-ètò ní ilé-iṣẹ́ Naija FM 102.7FM, ilé-iṣẹ́ Ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ tí ó jẹ́ ti ìbílẹ̀.

Ìgbé ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí gbémi ní (July 18, 1984) ní ìdílé Ọba Ọlágbẹ́gi ní ìlú Ọ̀wọ̀, ní ìpínlẹ̀ Òndó. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Pampers private school, ní ìlú Sùúrùlérè, àti ilé-ẹ̀kọ́ Nigerian Navy Secondary School,ní ìlú Ọ̀jọ́. Bákan náà ni ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Queens college,ní ìlú Yábàá lẹ́yìnnèyí ninó lọ sí ìlé-ẹ̀kọ́ àgbà Oakland University, níbibtí ó ti gbọoyè àkọ́kọ́ nínú iṣẹ ìròyìn, ìyẹ́n ( Mass Communication). Ó gba oyè ẹlẹ́kejì ìyẹn (Masyer's degree) nínú (Media and Communication) láti ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Pan African, ní ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2009.

Awọn àmì ẹ̀yẹ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó gba (future awards) ní ọdún 2008, fún - "On Air Personality of the Year". Ó tún gba àmì ẹ̀yẹ (Dynamix Awards) fún 'Atọ́kù ètò orì Rédíò tó peregedé jùlọ' ní ọdún 2008. Ó tún gba àmì ẹ̀yẹ́ "Green Awards for Excellence" fún ẹ̀ka ètò orí Rédíò ní ọdún 2008 bákan náà. Ní ọdún 2009, ó gba àmì ẹ̀yẹ "Exquisite Lady of the Year" fún (atọ́kù ètò obìnrin tó peregedé jùlọ). Ní ọdún 2010, wòn tún tun yàn fún "The Future Awards" fún ìgbà kejì. Ó tún gba àmì ẹ̀yẹ "City People Awards & The Nigerian Media Merit Awards in 2016 for On Air Personality of the Year"

Ẹ̀bùn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Award Category Result
2008 The future awards On Air Personality of the Year Gbàá
2008 Dynamix Awards Radio Presenter of the year Gbàá
2008 Green Awards for Excellence Radio Category Gbàá
2009 Exquisite Lady of the Year Best female radio presenter Gbàá
2016 City People Awards On Air Personality of the Year Gbàá
2016 The Nigerian Media Merit Awards On Air Personality of the Year Gbàá

Àwọ́n ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. . 
  2. . 
  3. Empty citation (help) 
  4. . 
  5. . 
  6. . 
  7. . 
  8. . [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]