Genny Uzoma

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Genny Uzoma
Ọjọ́ìbíNigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaEnugu state University Nigeria
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2005–present

Genny Uzoma jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] Ó sì tún jẹ́ Ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Enugu ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Genny ka ìwé gboyè ní Ilé Ẹ̀kọ́ gíga ti Ìpínlẹ̀ Enugu. Òsì jẹ́ òsèré orí ìtàgé. Ó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe eré ìtàgé ní ọdún 2005, ó sì ń ṣe títí dòní.

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Genny sí Ìpínlẹ̀ Ẹnúgu, ìbẹ̀ sì ní o dàgbà sì.[2] Ó jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Ímò. Ó gboyè jáde nínú ìmò òṣèlú láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Enugu State University of Science and Technology.[3]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Uzoma bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe eré nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìdínlógún.[4][5] Ó gbà àmì ẹ̀yẹ Revelation of The Year láti ọ̀dọ̀ Best of Nollywood Awards ní ọdún 2015.[6] Ní ọdún 2018, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ Most Promising Actress láti ọ̀dọ̀ City People Movie Award.

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • I wish She Would
  • The Shopgirl
  • Birthday Bash
  • Husbands of Lagos[7]
  • The Vendor
  • Our Society
  • Best of the Game
  • Classical Fraud
  • Royal Doom
  • Eagles Bride
  • Who killed Chief
  • A Love story
  • Emem and Angie
  • Reconciliation
  • The Gateman
  • Baby Shower
  • Baby mama
  • Commitment Shy
  • Scream
  • A face in the Crowd
  • Caught in between
  • King of Kings
  • Love in the wrong places
  • The washerman
  • Once upon an adventure
  • Bond (2019)

Àwọn Ìtọ́kàsi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]