Hammed Adio
Ìrísí
| Òrọ̀ ẹni | |
|---|---|
| Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
| Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kínní 1959 |
| Sport | |
| Erẹ́ìdárayá | Sprinting |
| Event(s) | 100 metres |
Hameed Adio
Listen (Eni tí wọ́n bí ní ọgúnjó oṣù kìíní ọdún 1959) jẹ́ Asáré orí páápá ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó díje nínú ìdíje 100 mítà àwọn ọkùnrin ní Olympic Ìgbà Òtútù ti ọdún 1980. Ó tún jẹ́ olórí àwọn aṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sí àwọn eré náà. [1]
Ó ti jẹ́ olùgbéròyìnjáde tẹ́lẹ̀ pẹ̀lú Nigeria Television Authority tó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùdarí ìròyìn eré ìdárayá nígbà tó ń sọ̀rọ̀ nípa ìdíje FIFA World Cup ọdún 1998 àti ìdíje IAAF World Championships ọdún 1999 ní Seville. [1]