Jump to content

Harrison Ford

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Harrison Ford
Ford ní ọdún 2017
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Keje 1942 (1942-07-13) (ọmọ ọdún 82)
Chicago, Illinois, U.S.
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1964–present
WorksFull list
Political partyDemocratic
Olólùfẹ́
Àwọn ọmọ5
AwardsFull list
Vice Chair of Conservation International
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1991 (1991)
AsíwájúPosition established

Harrison Ford (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1942) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ti farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, ọ̀pọ̀ sì mọ́ sí cultural icon orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.[1] Àwọn eré tí ó ti ṣeré ti pa tó iye owó tí ó lé ní bílíọ́nù márùn-ún dọ́là ní Àríwá Amẹ́ríkà àti iye tí ó lé ní bílíọ́nù mẹ́sán dọ́là káàkiri àgbáyé,[2] Ó ti gba ọ̀pọ̀ àmì-ẹ̀yẹ bi AFI Life Achievement Award ní ọdún 2000, Cecil B. DeMille Award ní ọdún 2002, Honorary César ní ọdún 2010, àti Honorary Palme d'Or ọdún 2023, wọ́n sì ti yàn rí mọ́ ara àwọn tí ó tọ́ sí àmì ẹyẹ Academy.[3][4]

Díè nínú àwọn eré tí ó ti ṣeré ni American Graffiti (1973), The Conversation (1974), Star Wars (1977), Raiders of the Lost Ark (1981), Blade Runner (1982) àti Blade Runner 2049 (2017), Patriot Games (1992), Clear and Present Danger (1994).

Wọ́n yan Ford mọ́ ara àwọn tí ó tọ́ sí àmì ẹyẹ Academy Award for Best Actor fún ipa rẹ̀ nínú eré Witness (1985).

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Harrison Ford: An Icon Turns 80". Golden Globes. Retrieved July 13, 2022. 
  2. "Harrison Ford Movie Box Office Results". Box Office Mojo. Retrieved August 12, 2019. 
  3. "Harrison Ford To Be Honored At Golden Globes". Washington Post. https://www.washingtonpost.com/archive/lifestyle/tv/2002/01/20/harrison-ford-to-be-honored-at-golden-globes/ead04d88-4c9d-4bd9-994c-353e4b6a7711/. Retrieved May 18, 2023. 
  4. "Person: Harrison Ford". Associated Press. May 18, 2023. Retrieved May 18, 2023.