Helen Paul

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Helen Paul
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kàrún 1983 (1983-05-01) (ọmọ ọdún 40)
Lagos
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànTatafo
Helen Paul Bamisile
Iṣẹ́Comedian, actress, singer
Websitehelenpaulacademy.com

Helen Paul jẹ́ aláwàdà, ólórin àti òṣèré orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2] Ó tún máa ń ṣiṣẹ́ ìpanilẹ́rìn-ín rẹ̀ lórí ètò "stand up Nigeria", Tatafo sì ni a mọ̀ ọ́ sí lórí ìtàgé. Ohun tó yà á sọ́tọ̀ ni óhùn rẹ̀ tí ó dà bí ti ọmọdé bírín tí ó máa ń lò láti fí p

anlẹ́rìn-ínn.[3]

Àìpẹ́ yìí ni ó gbóyè Doctorate nínú Theater Arts láti yunifásítì ilu-ékó

3

eko University of Lagos.[4]

Iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Paul ti ṣiṣẹ́ ìgbétò sáfẹ́fẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ìgbétò sáfẹ́fẹ́ bíi Lagos Television (LTV 8),Continental Broadcasting Service (CBS), àti MNet (níbi tí ó ti jùmọ̀ pẹ̀lú àwọn mìíràn gbé ètò JARA sí orí Africa Magic) ní Nàìjíríà.[5]

Ó di gbajúmọ̀ látipasẹ̀ ṣísáwàdà rẹ̀ lórí ètò orí rédíò Wetin dey lórí Rédíò Continental 102.3FM ní ìpínlẹ̀ Èkó. Àwọn èèyàn mọ̀ ọ́ sí "Tatafo" lórí ètò orí rédíò náà.[6]

Iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní oṣù keje ọdún 2012, ó gbé orin rẹ̀ Welcome Partyjáde. Àwọn orin Afro-Pop bíi "Bojú Bojú", "Vernacular", "Gbedu", "God forbid", orin Afro RnB "Children of the World" àti "Use Calculator(orin ẹ̀kọ́ kan nípa HIV/AIDs)" wà nínú àwo orin náà. Ní ọdún 2018, ó gbé orin audio àti video rẹ̀ "Never Knew" jáde.[7][8]

Àtòjọ àwọn eré tí ó ti ṣe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 2011 - The Return of Jenifa – role of Tunrayo[9]
  • 2012 - A Wish[10] – lead role, a woman who battles cancer
  • 2011 - Damage[11] – cameo role
  • 2012 - The Place: Chronicle of the Book[12]
  • 2014 - Alakada2[13] – supporting role
  • 2014 - Akii The Blind[14] – supporting role
  • 2012 - Osas (Omoge Benin)[15] – comic act
  • 2012 - Igboya[16]
  • Mama Put[17] – lead role

Ààtò àwọn àmì ẹ̀yẹ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 2012 African Film Awards (Afro-Hollywood, UK)[18] – Comedienne of the Year
  • 2012 Exquisite Lady of the Year Award (Exquisite Magazine)[19][20] – Female TV Presenter of the Year
  • 2014 Exquisite Lady of the Year Award (Nominated)[21] – TV Presenter of the Year (Jara, Africa Magic)
  • 2014 Nigerian Broadcasters Merit Awards (NBMA) – Outstanding TV presenter (Female) (Entertainment/Talk Show)[22]
  • 2011 City People Entertainment Magazine Award[23] – Female Comedian of the Year

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Akande, Victor (27 May 2012). "A-list comedians for 'Helen Paul & Tatafo Live'". The Nation (Lagos, Nigeria). http://www.thenationonlineng.net/2011/index.php/saturday-magazine/weekend-treat/entertainment/47940-a-list-comedians-for-%E2%80%98helen-paul-%26amp%3B-tatafo-live%E2%80%99.html. Retrieved 11 November 2012. 
  2. Adetu, Bayo (6 August 2010). "Growing Up Was Tough". P.M. News (Lagos, Nigeria). http://pmnewsnigeria.com/2010/08/06/growing-up-was-tough/. Retrieved 11 November 2012. 
  3. Kettle, James (2 November 2012). "The rising stars of world standup". The Guardian (London, UK). https://www.theguardian.com/stage/2012/nov/02/worlds-favourite-stand-ups. Retrieved 11 November 2012. 
  4. babtunde, Saka. "Celebrity Helen Paul was Born out of". www.newsliveng.com. Archived from the original on 2019-04-18. Retrieved 2019-04-09. 
  5. "Jara: Helen Paul". Africa Magic Official Website - Jara: Helen Paul (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-12-05. 
  6. Falae, Vivian (2017-07-13). "This is why we ♥love♥ Helen Paul". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-09. 
  7. Amoran, Moyosola (20 July 2012). "Tatafo Veers Into Music". P.M. News (Lagos, Nigeria). http://pmnewsnigeria.com/2012/07/20/tatafo-veers-into-music/. Retrieved 11 November 2012. 
  8. Ogunjimi, Opeoluwani (11 August 2012). "Helen Paul drops Boju Boju". Vanguard (Lagos, Nigeria). http://www.vanguardngr.com/2012/08/helen-paul-drops-boju-boju/. Retrieved 11 November 2012. 
  9. http://www.yorubafilm.com/headlines/3020-the-return-of-jenifa.html
  10. "Nollywood/ Nigeria No.1 movies/ films resources online". nigeriafilms.com. Archived from the original on 30 December 2014. Retrieved 12 February 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. "Damage | African Movie | Nollywood Forever Movie Reviews". nollywoodforever.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-02-09. Retrieved 2017-12-22. 
  12. "BFFs Uche Jombo and Desmond Elliot produce 'The Place' - Nigerian Entertainment Today". thenet.ng. 30 May 2013. Retrieved 12 February 2017. 
  13. "金沙网投登入_6165金沙国际_欢迎您!". Archived from the original on 2014-12-26. Retrieved 2020-01-21. 
  14. "Akii the Blind Nigerian Movie [Part 1] - Family Drama". nigeriamovienetwork.com. Retrieved 12 February 2017. 
  15. 9aijabooksandmovies (11 July 2012). "Osas (Omoge Benin) on VCD". wordpress.com. Retrieved 12 February 2017. 
  16. "Archived copy". Archived from the original on 2014-12-26. Retrieved 2014-12-26.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  17. "Mama Put by Helen Paul". Nigeria news live. Archived from the original on 18 April 2019. Retrieved 12 February 2017. 
  18. "Tonto, Helen Paul with Afro Nollywood awards - Vanguard News". vanguardngr.com. 27 October 2012. Retrieved 12 February 2017. 
  19. "Exquisite Ladies of the Year (ELOY) Awards 2012 brings all the glamour to Lagos (PHOTOS) - YNaija". ynaija.com. 29 November 2012. Retrieved 12 February 2017. 
  20. "BN Saturday Celebrity Interview: Who is Nigeria's top Comedienne, Singer, Actress, Compere & Presenter all rolled in one? It's Helen Paul, the Lady with Many Talents!". bellanaija.com. 2012-09-22. Retrieved 12 February 2017. 
  21. "Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo'Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. 2014-10-20. Retrieved 20 October 2014. 
  22. "DJ Xclusive, Helen Paul, IK Osakioduwa & More Emerge Winners at Nigerian Broadcasters Merit Awards (NBMA) 2014 -Full List of Winners". bellanaija.com. 2014-11-17. Retrieved 12 February 2017. 
  23. "Helen Paul in Nigeria". mydestination.com. Retrieved 12 February 2017.