Jump to content

Ibadan malimbe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Taxonomy not available for Malimbus; please create it automated assistant
Ibadan malimbe
4. ventral plumage of male
Ipò ìdasí
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/MalimbusMalimbus ibadanensis
Elgood, 1958

Ibadan malimbe ( Malimbus ibadanensis ) jẹ eya ẹyẹ ti o ṣọ̀wọ́n ninu ìdile Ploceidae .

Ó jẹ́ ẹyẹ to gbalẹ̀ ni ìpínlẹ̀ Nàìjíríà nikan, pàápàá jùlo ni apá gúúsù ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè náà, títí kan ìlú Ìbàdàn (ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́) tí wọ́n fi so ní orúkọ. Wọn kọkọ ṣe awari rẹ̀ ni ọdun 1951 àti pé ó wọ́pọ̀ ní ìgbà kan. Sùgbọ́n igbó sìsán jẹ́ kí o ṣọ̀wọ̀n.[2]

Ẹyẹ naa gùn ni ogún (20) sẹ̀ntímítà. Akọ ẹyẹ náà dúdú pẹ̀lú orí àti àyà pupa. Abo na a si ma ni pupa díẹ̀.

Ẹyẹ naa máa ń wá oúnjẹ ní méjì-méjì tàbí ní ẹgbẹ kékeré, nígbà míràn pẹ̀lú malimbe ti o ni ori pupa ( Malimbus rubricollis ). O ngbe ni igbo ati ibugbe inu igi, pẹlu awọn agbegbe ti o bajẹ.[3]

Àdàkọ:Ploceidae